Oṣù

(Àtúnjúwe láti Osù)

Osù jemó ìgbà tàbí àkókò tí a n lo ìwé-ìwo ojó fún tí àyípadà rè sì máa n pé bíi ojú ojó tí ó sì farapé bí òsùpá se n sisé. Osù àti òsùpá ní ìbásepò tó dánmórán.

Kí a tólè mo bí osù se n sisé, a gbódò ní òye púpò nípa bí òsùpá se n sisé. Òdiwòn tí òsùpá àti osù fi n sisé kòju "ókàn dín lógbòn sí métà lé láàdóta ojó lo (29.53) days.Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe