Oserheimen Osunbor

Olóṣèlú Nàìjíríà
(Àtúnjúwe láti Osariemen Osunbor)

Oserheimen Osunbor je oloselu ara ile Naijiria ati Alagba lati Edo ni Ile Igbimo Asofin lati 1999 titi de 2007. Ohun si lo tun ti je Gomina Ipinle Edo lati 2007 de 2008.

Ojogbon Oserheimen Osunbor, níbití o ti n ba egbé àwon olùkó ti ilè Nàìjíríàn (NUT) sọrọ, ní ojó karùn ún oṣù kẹwàá odún 2015, ní papa ìseré Samuel Ogbemudia, Ìlú Benin.