Oscar Ukonu
Oscar Ukonu (tí wọ́n bí ní ọdún 1993[1]) jẹ́ ayàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó ń gbé ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó gbajúmọ̀ fún àwọn àwòrán rẹ̀ tó máa ń jọ òótọ́.[2]
Oscar Ukonu | |
---|---|
Ilẹ̀abínibí | Nigerian |
Training | The Federal Polytechnic, Owerri |
Movement | Hyperrealism |
Ibiàwọn | https://www.oscarukonu.com |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Ukonu ní ọdún 1993. Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ya àwòrán nígbà tó wà ní ọmọdún mẹ́sàn-án. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nípa ìmọ̀ architecture ní Federal Polytechnic ní Nekede, Nàìjíríà.[3][4]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeLásìkò tó ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa architecture, ó ya ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwòrán pẹ̀lú pẹ́ńsù àti íǹkì láti ṣe idasile sítáì rẹ̀. Ní ọdún 2014, ó yan gègé ballpoint fún àwọn àwòrán rẹ̀. Wọ́n máa ń pe iṣẹ́ rẹ̀ ní hyperrealism àti Afrorealism. [5]
Iṣẹ́ kan lè gbà á tó ọ̀sẹ̀ mẹ́fà, tí ó sì máa lò tó gègé mẹ́wàá.[6][7] Ní ọdún
In 2iṣẹ́ rẹ̀, ìyẹn sion Bluewà ní ipò kẹfà ní ìdíje h in Sociétition.[8][9]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Ukonu, Oscar. "Biography". OSCAR UKONU. Retrieved 10 March 2022.
- ↑ Egbedi, Hadassah (11 May 2017). "Talented Nigerian artist, Oscar Ukonu, creates brilliant, photorealistic drawings using a ballpoint pen". Ventures Africa. Retrieved 10 March 2022.
- ↑ Enwonwu, Oliver (November 2016). "Insanity: An Exhibition of Hyperrealist Art". Omenka Gallery. Archived from the original on 21 May 2022. Retrieved 10 March 2022.
- ↑ Amadi, Osa (24 February 2020). "BIC as brush, medium and palette: An innovation of Art Masters". Vanguard. Retrieved 10 March 2022.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedOSCAR UKONU2
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedCyprus Mail
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedInsider.com
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedVanguard2
- ↑ Cai, Maggie; Brzezinski, Dylan (31 December 2020). "Artist draws hyperrealistic portraits using Bic ballpoint pens". Insider.com.