Osinachi Ohale jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 21, óṣu December ni ọdun 1991. Elere naa ṣère fun Spanish Primera Division Club Deportivo Alaves ati apapọ team awọn obinrin ti órilẹ ede naigiria[1][2].

Osinachi Ohale
Osinachi_Ohale_(cropped)
Personal information
OrúkọOsinachi Marvis Ohale
Ọjọ́ ìbí21 Oṣù Kejìlá 1991 (1991-12-21) (ọmọ ọdún 33)
Ibi ọjọ́ibíOwerri, Imo State, Nigeria
Ìga1.76 m
Playing positionDefender
Club information
Current clubDeportivo Alavés Gloriosas
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2008–2009Rivers Angels
2010–2014Delta Queens
2014Houston Dash19(1)
2015–2017Rivers Angels
2017–2018Vittsjö GIK22(1)
2018–2019Växjö DFF25(0)
2019–2020CD Tacón15(2)
2020A.S. Roma Women2(0)
2021Madrid CFF16(2)
2021–Deportivo Alavés Gloriosas5(1)
National team
Nigeria women's national football team26(1)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 19:33, 13 October 2021 (UTC)
**Source: Houston Dash.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 15:53, 17 June 2015 (UTC)

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Osinachi kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ Afirica nibi ti o jẹ àṣoju orilẹ ede naigiria ni ọdun 2010, 2014, 2016 ati 2018. Elere naa tun kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agabaye to waye ni ọdun 2011, 2015 ati 2019[3].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://int.soccerway.com/players/osinachi-ohale/135308/
  2. https://fbref.com/en/players/063a0372/Osinachi-Ohale
  3. https://www.foxsports.com/soccer/fifa-womens-world-cup/osinachi-ohale-player