Otosirieze Obi-Young
Oníwé-Ìròyín
Otosirieze Obi-Young (tí a bí ní ọdún 1994) jé òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria, olóòtú àti akọ̀ròyìn. Ó jẹ́ olóòtú àgbà fún Open Country Mag, èyí tó jẹ́ ìwé-ìròyìn tó sọ nípa ilẹ̀ Africa, àti àwọ lítíréṣọ̀ rẹ̀.[1] Ó jẹ́ olóòtú ti Folio Nigeria, èyí tó jẹ́ apá kan CNN, tó ń sọ̀rọ̀ nípa iṣẹ́-ọnà orílẹ̀-èdè Naijiria, ìdókòwò rẹ̀ àti eré-ìdárayá rẹ̀.[2] Ó jẹ́ igbákejì olóòtú ti ìwé-ìròyìn orí ẹ̀rọ-ayélujára Brittle Paper. [3][4] Ní ọdún 2019, ó jáwé olúborí, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ The Future Awards Africa fún lítírẹ́ṣọ̀.[5][6][7]
Otosirieze Obi-Young | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1994 (ọmọ ọdún 29–30) Aba, Ìpínlẹ̀ Abia, Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Yunifásitì ti Nàìjíríà, Nsukka |
Iṣẹ́ |
|
Organization |
|
Website | https://otosirieze.com/ |
Àwọn iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeÀwọn ìtàn kúkurú
àtúnṣe- A Tenderer Blessing.
- Mulumba.
- Pride and Prejudice: African Perspectives on Gender, Social Justice and Sexuality.
Àkọsílẹ̀ rẹ̀ lórí àṣà
àtúnṣe- "Chimamanda Ngozi Adichie Is in a Different Place Now", Open Country Magazine, 2021 [8]
- "How Teju Cole Opened a New Path in African Literature", Open Country Magazine, 2021[9]
- "Cameroon's New Literary Generation Comes of Age, as Anglophone Crisis Deepens", Open Country Magazine, 2021[10]
- "With Novels and Images, Maaza Mengiste Is Reframing Ethiopian History", Open Country Magazine, 2021[11]
- "The Making of Ndebe, an Indigenous Script for the Igbo Language", Folio Nigeria, 2020
- "In the Age of Afrobeats, a New Sound for Highlife", Folio Nigeria, 2020
- "In Nigeria, Investigative Journalism Finds Culture Impact", Folio Nigeria, 2020
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣe- 2019: The Future Awards Africa Prize for Literature
- 2020: The 100 Most Influential Young Nigerians, by Avance Media.[12]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Obi-Young, Otosirieze (17 September 2021). "Chimamanda Ngozi Adichie Is on the September 2021 Cover of Open Country Mag". Open Country Mag. Retrieved 4 May 2022.
- ↑ Clement, Phillips (18 May 2020). "Folio Group appoints Otosirieze Obi-Young as editor". https://dailytimes.ng/folio-group-appoints-obi-young-as-writer-editor/.
- ↑ Bedingfield, William (9 April 2018). "Eight Nigerian authors discuss Nigeria's literary culture". Dazed Digital. Retrieved December 25, 2018.
- ↑ "Otosirieze : Statement on Leaving Brittle Paper". Otosirieze (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-15. Retrieved 26 April 2020.
- ↑ "Burna Boy, Israel Adesanya, Timini Egbuson, Simi 'Drey' Adejumo, Tolani Alli, others emerge winners at The Future Awards Africa 2019". The Future Awards Africa. 26 November 2019. https://awards.thefutureafrica.com/burna-boy-israel-adesanya-timini-egbuson-simi-drey-adejumo-tolani-alli-others-emerge-winners-at-the-future-awards-africa-2019/. Retrieved 22 January 2020.
- ↑ "Burna Boy, Tolani Alli, Isaac Success … Meet the Winners at The Future Awards Africa 2019!". Bella Naija. 25 November 2019. Retrieved 26 November 2019.
- ↑ Ibeh, Chukwuebuka (November 24, 2019). "Otosirieze Obi-Young Wins Inaugural The Future Awards Prize for Literature". https://brittlepaper.com/2019/11/otosirieze-obi-young-wins-inaugural-the-future-awards-africa-prize-for-literature/.
- ↑ Obi-Young, Otosirieze (2021-09-20). "Cover Story: Chimamanda Ngozi Adichie on Half of a Yellow Sun at 15, Her Private Losses, and Public Evolution". Open Country Mag (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-09.
- ↑ Obi-Young, Otosirieze (2021-07-04). "Cover Story: How Teju Cole Opened a New Path in African Literature". Open Country Mag (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-09.
- ↑ Obi-Young, Otosirieze (2021-06-25). "In Cameroonian Literature, a New Generation Comes of Age". Open Country Mag (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-09.
- ↑ Obi-Young, Otosirieze (2021-01-16). "Maaza Mengiste's Chronicles of Ethiopia". Open Country Mag (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-09.
- ↑ "Profiles: 2019 100 Most Influential Young Nigerians". Avance Media. Retrieved 19 August 2020.