Ouidad Elma jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ ède Fránsì àti Morocco.[1] A bi ní ọjọ́ kejì oṣù Kẹ̀wá ọdún 1992 sí agbègbè Rif Mountains, ní Morocco. Ó sì dàgbà sí Paris ní orílẹ̀ ède Fránsì.

Ouidad Elma
Ọjọ́ìbíRif Mountains, Morocco
Orílẹ̀-èdèFrench and Moroccan
Iṣẹ́Actress

Ìpìlẹ̀ rẹ̀

àtúnṣe

Elma bẹ̀rẹ̀ sí ń kọ́ nípa òṣeré nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́fà. Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ń kópa nínú àwọn eré ní nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún. Àkọlé eré tí ó ti kọ́kọ́ kópa ni "Sa raison d'être", Renaud Bertrand ni ó dárí eré yìí. Lẹ́yìn náà ni ó kópa nínú eré "Plan B" tí Kamel Saleh dárí. Lẹ́yìn èyí, ó padà sí Morocco láti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré. Àpẹẹrẹ àwọn eré yìí ni "Love The Medina", "Zero" "The Rif Lover" àti L'Amante du Rif directed.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Ouidad Elma". IMDb. Retrieved 2017-10-13.