Owó ni ohunkóhun tí àwọn ènìyàn kan bá gbà lágbègbè, ìlú tàbí orílẹ̀-èdè wọn láti máa fi ṣe kárakáta ọjà tàbí san gbèsè. Ó jẹ́ ohunkóhun tàbí àkọsílẹ̀ tó dájú tí gbogbo ènìyàn gbà láti máa fi san owo ọjà rírà, iṣẹ́ tí a ṣe fúnni tàbí san gbèsè àti owó-orí. [1] [2] [3] Àwọn onímọ̀ ṣàlàyé pàtàkì Owó gẹ́gẹ́ bí ohun tí a fi ń ṣe pàṣípàrọ̀ ọ̀jà, nǹkan-ìdíyelọ́jà, nǹkan-ìdíyelé dúkìaí, àti nǹkan ipààlà iye ọjà. Ohunkóhun tí ó bá lè ṣe àwọn nǹkan wọ̀nyí ni a lè kà sí Owó.[4][5]

Owó pépà àti kọ́ìsì

Owó nínú ìtàn jẹ́ ohun to tọ́ tí a fi ń ṣe ìdókòwò ọja, àmọ́ ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ wípé owó láyé òde òní ni ónì ètò tó dálé

fiat money.[6] (Owó tí oun tí alè fojú rí bíi góólù tàbí sílífà kòlè rópò)

Fiat money[7], da bi sowe dowo tabi akosile fun eto isanwo, ko wulo laaye ara re.[citation needed]


Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Investopedia (2017-04-26). "What Is Money?". Investopedia. Retrieved 2019-10-08. 
  2. "What is money? definition and meaning". BusinessDictionary.com. 2019-10-03. Archived from the original on 2019-10-31. Retrieved 2019-10-08. 
  3. "Definition of MONEY". Definition of Money by Merriam-Webster. 2019-05-28. Retrieved 2019-10-08. 
  4. "Functions of Money". cliffsnotes.com. Retrieved 2019-10-08. 
  5. "Top 6 Functions of Money –Discussed". Economics Discussion. 2015-10-17. Retrieved 2019-10-08. 
  6. Mankiw, N. Gregory (2007). "2". Macroeconomics (6th ed.). New York: Worth Publishers. pp. 22–32. ISBN 978-0-7167-6213-3. https://archive.org/details/macroeconomics0000mank/page/22. 
  7. Tamplin, True (2021-06-08). "Fiat Money - Definition - Pros and Cons". Finance Strategists Helping People with Their Finances. Retrieved 2023-02-01.