Oxford Centre for Islamic studies

Ibi iṣẹ́-ìwádìí ní Oxford, England

Oxford Centre for Islamic Studies (OXCIS)

Oxford Centre for Islamic Studies building, operational from 2016.

Wọ́n daa sílẹ̀ ní ọdún 1985 gẹ́gẹ́ bí agbègbè ẹ̀kọ́ tí ó dá dúró tí ó ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú ilé ẹ̀kọ́ gíga Oxford ní pàtó fún  kíkọ́ ẹ̀kọ́ ẹ̀sìn Ìsìláámù àti àwọn agbègbè àwọn mùsùlùmí tí ó yanjú.[1] Bàba ẹgbẹ́ rẹ̀ jẹ́ Ọmọọba Wales. Ní 2012 Ọbabìrin Elizabeth II fún agbègbè ẹ̀kọ́ náà ní àmì ẹ̀yẹ ti ọba. Àwọn ìgbìmọ̀ tí wón ń ṣe àkóso rẹ̀ àwọn onímímọ̀ àti àwọn àgbà òṣèlú káàkiri àgbáyé àti àwọn aṣojú ilé ẹ̀kọ́ gíga Oxford[2][3][4]

The front courtyard inside the Oxford Centre for Islamic Studies, Oxford.

Ilé ẹ̀kọ́ náà gbá'júmọ̀ kíkọ́ ẹ̀kọ́ láti ẹ̀ka ẹ̀kọ́ oríṣiríṣi, àwọn  àṣà àti ọ̀làjú ìsìláámù tí àwọn mùsùlùmí òde òni. Agbègbè ẹ̀kọ́ náà ní àwọn akẹ́ẹ̀kọ̀ tí ó yáyì ní  àwọn ẹ̀ka ẹ̀kọ́, àgbajú ẹ̀ka ẹ̀kọ́, àti ilé ẹ̀kọ́ kéréje kéréje káàkiri ilé ẹ̀kọ́ gíga ọ̀hún. Ọ̀pọ̀ àwọn ọ̀tọ̀kùlú àti ọ̀mọ̀wé tí kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní ètò kan tí láti ọdún 1993 tí ọmọọba tí ìlú Wales ṣí'de rẹ̀ pẹ̀lú orí ọrọ̀ "Ìsìláàmù àti īlẹ̀ aláwọ̀ funfun. Àwọ̀ń olùdánilẹ́kọ́ fún irú ètò yìí jé àwọn olórí àti àwọn orílẹ̀-èdè, àwọn onímímọ̀ àgbáyé láti àwọn tí ẹ̀sìn Ìsìláámù ti fi ẹsẹ̀ múlẹ̀, àwọn akọ̀wé àgbà ní àwọn ìgbìmọ̀ àgbayé gẹ́gẹ́ bíi UN, OIC, Ìgbìmọ̀ àwọn Lárùbáwá (the Arab leagues), Àjọ tí ó ń rí sí àṣà àti ẹ̀kọ́ àwọn ọmọde (UNESCO) àti àjọ àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ṣepọ pẹ̀lú àwọn gẹ̀ẹ́sì (Common wealth of nations).[5][6][7][8][9][10][11]

Agbègbè ẹ̀kọ́ náà bẹ̀rẹ̀ ní ahéré onígi kan ní ọ̀na St Cross. En tún gbee lọ sí ilé ìgbé àwọn ọ́fììsì ní òpópó-ònà George nin1990.[12] En tún gbe e lọ sí ààyè tuntun tí ọmọ Íjíbítì (Egypt) oníṣẹ́ ọnà, Abdel-Wahed El-Wakil[13] bu ewà kún ní sáà ìkẹ́ẹ̀kọ́ tí 2016/2017.[14]

Àwọn itokasi

àtúnṣe
  1. "Palestinian Ambassador Afif Safieh at OXCIS Palestinian-Israeli Relations: History is Still Undecided". The Muslim Weekly (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 19 February 2019. Retrieved 2019-02-18. 
  2. "Prince 'Abdul Mateen graces Sultan of Brunei Prize presentation ceremony | Borneo Bulletin Online" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 19 February 2019. Retrieved 2019-02-18. 
  3. Binyon, Michael (2018-03-03). "Catholic Church sets out a vision for closer ties with Islam" (in en). The Times. ISSN 0140-0460. https://www.thetimes.co.uk/article/catholic-church-sets-out-a-vision-for-closer-ties-with-islam-ddzf9h7sm. 
  4. "Dr Wan Azizah visits Oxford Centre for Islamic Studies". Malay Mail (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 6 December 2018. Retrieved 2019-02-18. 
  5. "Palestinian Ambassador Afif Safieh at OXCIS Palestinian-Israeli Relations: History is Still Undecided". The Muslim Weekly (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 19 February 2019. Retrieved 2019-02-18. 
  6. "Prince 'Abdul Mateen graces Sultan of Brunei Prize presentation ceremony | Borneo Bulletin Online" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 19 February 2019. Retrieved 2019-02-18. 
  7. Binyon, Michael (2018-03-03). "Catholic Church sets out a vision for closer ties with Islam" (in en). The Times. ISSN 0140-0460. https://www.thetimes.co.uk/article/catholic-church-sets-out-a-vision-for-closer-ties-with-islam-ddzf9h7sm. 
  8. "Dr Wan Azizah visits Oxford Centre for Islamic Studies". Malay Mail (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 6 December 2018. Retrieved 2019-02-18. 
  9. OTHMAN, ZAHARAH (2018-09-23). "Dr M to deliver major lecture on Islam at Oxford Centre for Islamic Studies". NST. 
  10. Devenport, Mark (2018-09-13). "Seeing the human side of a UN chief" (in en-GB). https://www.bbc.com/news/uk-northern-ireland-45253853. 
  11. "A royal relationship: Prince Andrew honours Sheikh Zayed at centenary event". The National (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-02-18. 
  12. "Prince Charles urges population to 'rediscover unity' as he opens Islamic centre". Oxford Mail (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-02-18. 
  13. "Abdel-Wahed El-Wakil or the Triumph of the Islamic Architectural Style". Muslim Heritage. 2009-10-27. Retrieved 2020-02-18. 
  14. "£60m Islamic studies centre to open at last". Oxford Mail (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-02-18. 
àtúnṣe


Àdàkọ:University of Oxford

Àdàkọ:Authority control


Àdàkọ:Oxfordshire-struct-stub Àdàkọ:Islam-org-stub