Oxlade
Ikúforíjì Oláìtán Abdulrahman, tí ayé mọ sí Oxlade, jẹ́ Ọ̀kọrin àti Olórin tí wà lábé ilé iṣé orin kàn ní orílé èdè faransé tí ó ń jẹ́ Troniq Music, ẹ̀ka Epic records àti ilé iṣé orin mìíràn ní U.K tí orúko rẹ̀ ń jẹ́ Fuenlabrada Records.[1] Ó di olókìkí nígbà tí orin tí ó pè ní Away jáde tí ó jẹyọ nínú àwọn àádọta orin tí Rolling Stone fẹràn julọ ní 2020. Oxlade gbà orúkọ àti àmì Africa's Next Artist ni Pandora Alákọkọ́ ní ọdún 2022. [2]
Oxlade | |
---|---|
Oxlade lórí WazobiaMax TV ni 2019 | |
Ọjọ́ìbí | Ikuforiji Olaitan Abdulrahman Surulere, Lagos |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2018–present |
Musical career | |
Irú orin | Afro-fusion, R&B, alternative pop |
Instruments | Vocalist |
Labels |
|
Website | www.oxladeofficial.com |
Àwọn Àríyànjiyàn
àtúnṣeNi ọjọ kejìdínlógún ọdún 2020, Oxlade wà lára àwọn tí wọn fara pa ni ìgbà ìfi ẹ̀honú hàn tí EndSARS ní Surulere, agbègbè kan ní Ìpínlè Èkó. Àwọn olùgbé àti àwọn tí wọn jáde láti fí fi ẹ̀honú hàn pé àsìkò yìí àti ìsèlè náà lórí àwọn èrò ayélujára ní #EndSARS, nínú àgekurú fídíò kan tí olusàkóso Oxlade ti orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ojah'B gbé sójú ẹrọ internet ní a tí rí àwọn ọlọpa tí lùú níbi tí wọn tiń fi agbára pa àtakò náà. [3]
Ni ọjọ kẹjọ, oṣù Kejì ọdún 2022 ni téèpù fídíò ìbálòpọ̀ tí Oxlade jáde sórí ẹ̀rọ Ayélujára Snapchat, èyí tí ódi ohun àríyànjiyàn lórí èrò Twitter.[4] Ní oṣù Kejì ọjọ kẹwàá Ọdún 2022, Obìnrin inú Téèpù náà jáde pé òun yóò pé Oxlade ní ẹjọ́ , èyí tí ilé ẹjọ ní kìí Oxlade san ogún mílíọ́nù náírà.[5] Ní ọjọ kejìlélógún oṣù Kejì, odun náà ní Oxlade tọrọ Ìdáríjì lórí Twitter lọ́wọ́ àwọn olólùfẹ́ rẹ àti obìnrin tí ó wà nínú fídíò náà.[6]
Isẹ́ Ọnà
àtúnṣeGẹ́gẹ́ bí Ọ̀gbéni Efe Ukpebor tí ilé iṣẹ Nigerian Entertainment Today ṣe ṣàpèjúwe Ohùn Oxlade, ó ní, ohùn rẹ̀ dán bẹ́ẹ̀ síni ó wà ní ìbámu pẹ̀lú ìdàpọ̀ orin àlàígbẹ́.[7] Ó ṣẹ àpèjúwe ohùn rẹ̀ bí afárá láàrin Alte (Afro-fusion àti experimental music expressions) àti àwọn mainstream.[8]Àwọn orin rẹ̀ jẹ́ àdàlú Gẹ̀ẹ́sì, àti Pidgin English, nígbà gbogbo ní ó ń ṣàwarí àwọn kókó-ọ̀rọ̀ ìmísí gẹ́gẹ́ bí ìfẹ.
Àwọn Orin
àtúnṣeEPs
àtúnṣeTitle | EP details |
---|---|
Oxygene |
|
Eclipse |
|
Singles
àtúnṣeAs lead artist
àtúnṣeTitle | Year | Peak chart positions | Certifications | Album | |||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
NG [9] |
CAN [10] |
IRE [11] |
NLD [12] |
NZ Hot [13] |
SA [14] |
SWE [15] |
UK [16] |
US Afro. [17] |
WW [18] | ||||
"Away" | 2020 | —[upper-alpha 1] | — | — | — | — | — | — | — | — | — | Oxygene | |
"DKT" | — | — | — | — | — | — | — | — | — | — | Non-album single | ||
"Ojuju" | 2021 | 13 | — | — | — | — | — | — | —[upper-alpha 2] | — | — | Eclipse | |
"Want You" | 2022 | — | — | — | — | — | — | — | —[upper-alpha 3] | 47 | — | rowspan="2" Àdàkọ:TBA | |
"Ku Lo Sa" | 49 | 59 | 50 [21] |
13 | 22 | 5 | 35 | 24 | 5 | 79 |
As featured artist
àtúnṣeTitle | Year | Peak chart positions | Album | |
---|---|---|---|---|
NG |
UK Afro. [upper-alpha 4] | |||
"Interest" (with Dolago and Ms Banks) | 2021 | — | 10 | Àdàkọ:TBA |
"Kolo" (Ice Prince featuring Oxlade) | 8[26] | — | Àdàkọ:TBA |
Filmography
àtúnṣeYear | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
2020 | Like Someone's Watching | Oxlade | Main cast |
Awards and nominations
àtúnṣeYear | Event | Prize | Recipient | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2021 | African Entertainment Awards USA | Best New Artist | Himself | Wọ́n pèé | |
All Africa Music Awards | Best Artist, Duo or Group in African RnB & Soul | Wọ́n pèé | |||
2020 | City People Music Awards | Next Rated Artiste (Male) | Wọ́n pèé | ||
The Headies | Next Rated | Wọ́n pèé | |||
2019 | The Headies | Rookie of the year | Wọ́n pèé | ||
2022 | All Africa Music Awards | African Fan's Favorite | Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ | ||
2023 | Soundcity MVP Awards Festival | Song of the Year | Ku Lo Sa | Yàán | [27][28] |
Listener's Choice | Himself | Gbàá | [29] |
Àwọn Ìkọsílẹ̀
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Oxlade signs new deal with Columbia Records". The Nation Newspaper. 10 March 2022. Retrieved 19 March 2022.
- ↑ "Ní ọ̀pọ̀ ìgbà ní Oxlade máa ń ṣọ̀rọ̀ ní ìgbà gbogbo nípa bí àwọn oriṣiríṣi ọ̀kọrin àti òṣèré orin ṣe ń yọ jáde ní orílé èdè Nàìjíríà, èyí tí ó mú kí òun náà fẹ́ di olókìkí ní ìlú Ọba àti lórí ètò Pandora's Africa Next.". grungecake.com. Retrieved 14 July 2022.
- ↑ "Oxlade injured, manager arrested as #EndSARS protest turns violent". TheCable Lifestyle. 12 October 2020. Retrieved 19 March 2022.
- ↑ "How Oxlade's nude photos, sex tape leaked on Snapchat". Premium Times Nigeria. 9 February 2022. Retrieved 19 March 2022.
- ↑ "Oxlade in another trouble!". AlimoshoToday (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 19 March 2022.
- ↑ "Sex tape: Singer Oxlade apologises to fans, lady in video". Punch Newspapers. 12 February 2022. Retrieved 19 March 2022.
- ↑ "Meet Oxlade, the Nigerian Pop Artiste You Should Look Out For". Nigerian Entertainment Today. 11 May 2020. Retrieved 10 November 2021.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedThe Guardian Nigeria
- ↑ Peaks in Nigeria:
- "Ojuju": "Turntable Top 50: Kizz Daniel holds steady at No.1 with "Lie"". The Native. 23 August 2021. Retrieved 10 November 2021.
- "Ku Lo Sa": "Turntable Charts Top 50 Chart". Turntable Charts (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 23 July 2022.
- ↑ "Billboard Canadian Hot 100: Week of October 1, 2022". Billboard. https://www.billboard.com/charts/canadian-hot-100/2022-10-01/. Retrieved 27 September 2022.
- ↑ "IRMA – Irish Charts". Irish Recorded Music Association. Retrieved 1 October 2022.
- ↑ "Discografie Oxlade". dutchcharts.nl (in Èdè Dọ́ọ̀ṣì). Retrieved 8 October 2022.
- ↑ "NZ Hot Singles Chart". Recorded Music NZ. 22 August 2022. Retrieved 20 August 2022.
- ↑ "Local & International Streaming Chart Top 100 Week 37-2022". The Official South African Charts. Recording Industry of South Africa. Retrieved 23 September 2022.
- ↑ "Veckolista Singlar, vecka 38". Sverigetopplistan. Retrieved 23 September 2022.
- ↑ "Oxlade | full Official Chart History". Official Charts Company. Retrieved 10 November 2021.
- ↑ Cusson, Michael (29 March 2022). "Billboard U.S. Afrobeats Songs". Billboard. https://www.billboard.com/charts/billboard-u-s-afrobeats-songs/2022-03-29/. Retrieved 30 March 2022.
- ↑ "Billboard Global 200: Week of October 8, 2022". Billboard. https://www.billboard.com/charts/billboard-global-200/2022-10-08/. Retrieved 4 October 2022.
- ↑ "Official Afrobeats Chart Top 20 | Official Charts Company". www.officialcharts.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 10 November 2021.
- ↑ "Official Afrobeats Chart Top 20 | Official Charts Company". www.officialcharts.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 30 March 2022.
- ↑ "Top 100 Singles, Week Ending 14 October 2022". Official Charts Company. Retrieved 14 October 2022.
- ↑ Àdàkọ:Cite certification
- ↑ Àdàkọ:Cite certification
- ↑ Àdàkọ:Cite certification
- ↑ "Official Afrobeats Chart Top 20 | Official Charts Company". www.officialcharts.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 11 November 2021.
- ↑ "TurnTable Top 50: Teni's "For You" returns to No. 1". The Native. 12 April 2021. Retrieved 10 November 2021.
- ↑ Maganga, Charles (19 January 2023). "2023 Soundcity MVP Awards Nominations: The Complete List". Notjustok. Retrieved 20 January 2023.
- ↑ "Burnaboy, Black Sherif, Win At The Soundcity MVP Awards 2023 (FULL WINNERS LIST)". African Folder. Retrieved 12 February 2023.
- ↑ "Burnaboy, Black Sherif, Win At The Soundcity MVP Awards 2023 (FULL WINNERS LIST)". African Folder. Retrieved 12 February 2023.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "upper-alpha", but no corresponding <references group="upper-alpha"/>
tag was found