Oyèlẹ́yẹ jẹ orúkọ ọmọ Yorùbá ni orile-ede Nàìjíríà tí wọ́n ń fún ọmọ ọkùnrin. O jẹ orukọ akọ pẹlu orisun orúkọ Yoruba, eyiti o tumọ si " òye le fúnni ni iyì"

Awọn eniyan olokiki pẹlu orukọ

àtúnṣe
  • Oyeleye Oyediran, Onimo ijinle sayensi ati oselu Naijiria
  • Olateju Oyeleye (1924–2013), onisowo Naijiria
  • Oluwa Femi Oyeleye (ọjọ́ìbí 1994), afẹṣẹja Naijiria

Awọn itọkasi

àtúnṣe