Onyinyechi Salome Zogg (tí wọ́n bí ní 3 March 1997) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù tó ń gbá bọ́ọ̀lù nípò alátakò. Ìlú Switzerland ni wọ́n bí i sí, ó sì ṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ìdíje gbogboogbò.

Onyinyechi Zogg
Personal information
OrúkọOnyinyechi Salome Zogg[1]
Ọjọ́ ìbí3 Oṣù Kẹta 1997 (1997-03-03) (ọmọ ọdún 27)[2]
Ibi ọjọ́ibíBern, Switzerland
Ìga1.72 m[2]
Playing positionDefender[2]
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Young Boys16(1)
Femina Kickers Worb
FC Bethlehem
2019–2021Zürich35(4)
2021–2022ASJ Soyaux11(0)
2022–2023Turbine Potsdam3(0)
National team
2021–Nigeria2(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 7 May 2023.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 16 June 2021.[3]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Zogg sí ìlú Bern.[4] Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Switzerland, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ Nàìjíríà.

Iṣẹ́ rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Ilé-ìwé Monroe College ni Zogg lọ, ní United States.[4]

Iṣẹ́ rẹ̀ ní ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù

àtúnṣe

Zogg gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ BSC Young Boys, Femina Kickers Worb, FC Bethlehem àti Zürich ní Switzerland.

Iṣẹ́ rẹ̀ káàkiri àgbááyé

àtúnṣe

Zogg ṣe àfihàn ẹlẹ́ẹ̀kejì fún Nàìjíríà ní 10 June 2021 ní ayò ọlọ́rẹ̀ẹ́jọ́rẹ̀ẹ́, sí 0–1 sí Jamaica.[5]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Àdàkọ:Soccerway
  2. 2.0 2.1 2.2 "Onyinyechi Zogg". FC Zürich (in Èdè Jámánì). Archived from the original on 28 February 2022. Retrieved 19 June 2021. 
  3. "Salome Zogg". Global Sports Archive. Retrieved 19 June 2021. 
  4. 4.0 4.1 "Onyinyechi Zogg – Women's Soccer". Monroe College Athletics. Retrieved 19 June 2021. 
  5. "Match Report of Jamaica vs Nigeria – 2021-06-10 – FIFA Friendlies – Women". Global Sports Archive. Retrieved 19 June 2021.