Oyo State College of Agriculture and Technology
Oyo State College of Agriculture and Technology (OYSCATECH) jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga kan tí ó wà ní Ìgbò-Òrà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Nàìjíríà. Wọ́n dá ilé-ẹ̀kọ́ náà sílẹ̀ ní ọdún 2006, ó sì ń ṣàkóso nípa àgbé, ìmọ̀-èrọ àti àwọn ẹ̀ka ìmọ̀ mìíràn tí ó jọmọ́. Kọ́lẹ́ẹ̀jì náà ń pèsè orísirísi ètò ẹ̀kọ́, tí ó ń yọrí sí àmì ẹ̀yẹ-ẹ́rí, dìpọ̀mà, àti ìwé-ẹ̀rí nípa ìmọ̀-ọ̀gbìn, ẹ̀rọ, ìmọ̀ kọ̀mpútà àti àwọn ẹ̀ka tí ó jọmọ́..[1][2]
Ilé-ẹ̀kọ́ náà jẹ́ polytechnic tí Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní agbègbè Gúúsù Ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà. Ó ní ìmọ̀lára àṣẹ àti fọwọ́sowọ́lé látọ́run National Board for Technical Education (NBTE) ní orílẹ̀-ẹ̀dẹ̀ Nàìjíríà.[3]
Àwọn ètò èkó
àtúnṣeOyo State College of Agriculture and Technology ń pèsè orísirísi àwọn ẹ̀kọ́ nípa àgbé, ìmọ̀-èrọ àti àwọn ẹ̀ka tó jọmọ́, gégé bíi:[4]
- Agricultural Technology
- Animal Production and Health Technology
- Fisheries and Technology
- Public Administration
- Computer Science
- Statistics
- Business Administration and Management
- Estate Management and Valuation
- Urban and Regional Planning
- Agricultural Engineering Technology
- Electrical and Electronics Engineering Technology
- Crop Production and Protection Technology
- Vocational and Entrepreneur Training
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Oyo state College of Agriculture and Technology". Therealmina. Archived from the original on 2023-12-11. Retrieved 2023-12-14.
- ↑ Olawore, Opeyemi (2023-05-30). "Excellence in agric, technology and management: The OYSCATECH example". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-12-13.
- ↑ Olawore, Opeyemi (2023-05-30). "Excellence in agric, technology and management: The OYSCATECH example". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-12-24.
- ↑ "Lists of The Courses Offered at The Oyo State College of Agriculture and Technology (OYSCATECH) and Their School Fees". 9jaPolyTv (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-12-19. Retrieved 2023-12-13.