Ozak-Obazi Oluwaseyi Esu tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹrin ọdún 1991 tí ń ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ Electrical Engineer tí ó sì jẹ́ adarí ní Building Research Establishment, Centre for Smart Homes and Buildings (CSHB)][1]. Ó ti fìgbà kan ṣiṣẹ́ ní Cundall ní Birmingham, níbi tí wọ́n ti ń ṣẹ̀dá ohun ìkọ́lé lóríṣiríṣi.

Ozak Esu
ÌbíOzak-Obazi Oluwaseyi Esu
23 Oṣù Kẹrin 1991 (1991-04-23) (ọmọ ọdún 33)
Kaduna, Nigeria
PápáElectronic engineering
Ilé-ẹ̀kọ́Cundall Johnston and Partners
Ibi ẹ̀kọ́Loughborough University (BEng, PhD)
Doctoral advisorJames Flint
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síYoung Woman Engineer of the Year Award (2017)

Ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ìpínlẹ̀ Kaduna lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà ni a bí Ozak Esu sí. Ó parí A-Level examinations nínú mathematics, physics àti geography ní ìpínlẹ̀ Èkó.[2] Ìṣòro iná ní Nàìjíríà ló mu kẹ́kọ̀ọ́ nípa engineering ní university.[3] Àìríná lò lórílẹ̀-èdè náà ló jẹ́ ó fọkàn sí ẹ̀kọ́ Physics. [4]

Ní ọdún 2008, ó lọ sí UK níbi tí ó ti gboyè bachelor's degree nínú Electronic and Electrical Engineering. Òun ni ààrẹ Nigerian Society.[5] Ó gba ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ £54,000 fún postgraduate study, ó sì gboyè PhD lọ́dún 2016.[6]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Esu dara pọ̀ mọ́ Cundall Johnston and Partners ní oṣù kọkànlá ọdún 2014 gẹ́gẹ́ bíi onímò ẹ̀rọ tó kọ́ṣẹ́mọṣẹ́ tó sì ń ṣètò PhD ní Loughborough University.[7] Ó ti lọ́wọ́ sí technical design lóríṣiríṣi ó sì ti mójú tó kíkọ́ ilé-ìwé rẹpẹtẹ ní UK láàárín ọdún méjì tí ó fi wà ní ilé-iṣẹ́ náà.[8] Ó wà lára àwọn ọ̀wọ́ tó rí sí design ilé-iṣẹ́ Energy Systems Catapult ní Birmingham, tí ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ British Council for Offices ‘Fit Out of Workplace’ Midlands Regional Award lọ́dún 2017. [9][10][11] Ní ọdún 2017, wọ́n gbe lọ sípò electrical engineer [12]. Ipò tí ó wà yìí ló rí sí dídarí àti ṣíṣàkóso iṣẹ́ lámèyító, ó sì tún rí sí gbígba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ níyànjú.[13].

Ní oṣù kìíní ọdún 2019, Esu dara pọ̀ mọ́ BRE (Building Research Establishment) gẹ́gẹ́ bíi technical lead ní BRE Centre for Smart Homes and Buildings (CSHB) Archived 2019-08-06 at the Wayback Machine.[1].

Ipò tí Esu wà yìí ló rí sí ṣíṣe ìwádìí lóríṣiríṣi lórí àwọn iṣẹ́ tuntun àti pípèsè èròǹgbà fún iṣẹ́. Èyí sì fún láàyè láti mú ìmọ̀ PhD rẹ̀ sójú iṣẹ́.

Ààtò àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

àtúnṣe

Ní ọdún 2013, Esu jáwé olúborí fún Inaugural Energy Young Entrepreneur Scheme (Energy YES) tí ó ń lọ bíi £2,000 nígbà tí ó ń ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú àwọn èèyàn mẹ́rin mìíràn láti MEGS (Midlands Energy Graduate School).[14] Esu jẹ́ ọ̀kan lára àwọn "The Telegraph’s Top 50 Women in Engineering under 35" tí wọ́n ṣe ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹfà ọdún 2017.[15] Òun ló gba àmì-ẹ̀yẹ Institution of Engineering and Technology Young Woman Engineer of the Year ní ọdún 2017.[16][17] Ní oṣù kẹsàn-án ọdún 2017, ó gba àmì-ẹ̀yẹ tí Institution of Engineering and Technology Mike Sargeant Career Achievement Award for Young Professionals ní ìbámu pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ rẹ̀ lórí engineering àti technology.[18][19]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Fuller, Georgina (2019-06-25). "Why the energy industry needs more women in power" (in en-GB). The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/careers/2019/jun/25/women-in-power-why-the-energy-industry-needs-more-female-engineers. 
  2. "Nigerian Electrical Engineer, Dr. Ozak Esu, Named The IET Young Woman Engineer of 2017 in the UK" (in en-US). Levers in Heels. 2018-02-12. Archived from the original on 2018-02-17. https://web.archive.org/web/20180217024033/http://leversinheels.com/featured/nigerian-electrical-engineer-dr-ozak-esu-named-the-iet-young-woman-engineer-of-2017-in-the-uk/#.WocSzJOFiML. 
  3. "Nigerian Dr Ozak Esu named among Telegraph's "Top 50 Women in Engineering Under 35" - Media Room Hub". www.mediaroomhub.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-02-16. 
  4. IET (2017-12-13), My Story: Ozak Esu | Cundall #PortraitOfAnEngineer, retrieved 2018-02-17 
  5. "Ozak Esu | Loughborough Alumni | Loughborough University". www.lboro.ac.uk (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-02-16. 
  6. "Engineering | Construction Youth Trust". www.constructionyouth.org.uk (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-02-16. 
  7. "Dr Ozak Esu named in the Telegraphs Top 50 Women in Engineering - Cundall". www.cundall.com. Retrieved 2018-02-16. Àdàkọ:Verify source
  8. IET (2017-12-13), My Story: Ozak Esu | Cundall #PortraitOfAnEngineer, retrieved 2018-02-17 Àdàkọ:Verify source
  9. "Energy Systems Catapult – new industry hub made in Birmingham – ESC". es.catapult.org.uk. Retrieved 2018-02-17. Àdàkọ:Verify source
  10. "Two wins and one highly commended for three Cundall projects - Cundall". www.cundall.com. Retrieved 2018-02-17. Àdàkọ:Verify source
  11. "BCO - Fit Out of Workplace Award". www.bco.org.uk. Retrieved 2018-02-17. Àdàkọ:Verify source
  12. "Nigerian Electrical Engineer, Dr. Ozak Esu, Named The IET Young Woman Engineer of 2017 in the UK". Levers in Heels. 2018-02-12. Retrieved 2018-02-16. Àdàkọ:Verify source
  13. "Ozak Esu - Cundall". www.cundall.com. Retrieved 2018-02-16. Àdàkọ:Verify source
  14. "Energy Young Entrepreneurs Scheme (Energy YES) 2013" (PDF). Midlands Energy Graduate School. 2013. Archived from the original (PDF) on 2018-02-18. Retrieved 2018-02-17. 
  15. "Dr Ozak Esu named in the Telegraphs Top 50 Women in Engineering - Cundall". www.cundall.com. Archived from the original on 2018-02-17. Retrieved 2018-02-16. 
  16. "Meet the new faces of engineering". the Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-02-16. 
  17. "Dr Ozak Esu crowned Young Woman Engineer of the Year - Cundall". www.cundall.com. Archived from the original on 2018-02-17. Retrieved 2018-02-16. 
  18. "Cundall Engineer Dr. Ozak Esu Given Institute of Engineering and Technology Award" (in en-GB). BDC Magazine. 2017-09-27. http://www.bdcmagazine.com/cundall-engineer-dr-ozak-esu-given-institute-engineering-technology-award/. 
  19. "Dr. Ozak Esu Announced as Mike Sergeant Award Winner by IET" (in en-US). Property & Development. 2017-09-27. Archived from the original on 2018-02-17. https://web.archive.org/web/20180217085511/http://www.padmagazine.co.uk/business-money-legal-jobs/dr-ozak-esu-announced-mike-sergeant-award-winner-iet-10182.