Ìgbaná: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Xqbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
Ìlà 1:
'''Ìgbaná''' tabi '''ìjóná''' ni a n pe gbogbo ifesi alegbogi (chemical reaction) to n mu igbona ati imole wa.
Igbana je ifesi Iresile-Isodioloksijini. Ni igba atijo won n pe gbogbo ifesi mo oksijini (O<sub>2</sub>) to mu igbona ati imole wa ni igbana. Sugbon loni a mo pe awon ohun alara miran na le fa orisi igbana. Iru awon ohun alara bayi ni Florini (F<sub>2</sub>) , Klorini (Cl<sub>2</sub>) at.bb.lo. Botiwukoje ni igba ti a ba n soro nipa igbana, lai se itumo mo ohun kankan, o tumo si igbana mo oksijini tabi afefe. Ni pataki awon igbana adapo alemin (organic compound) n sele pelu O<sub>2</sub> tabi pelu awon ohun alara to ni oksijini bi afefe tabi baba oloksijini(II) (CuO).
 
 
== Irú ìgbaná ==
A le pin igbana si eyi '''topari''' ati eyi '''tikopari''' gege bi iye O<sub>2</sub> to wa ati awon ìwàkání igba na.
 
* ''Igbana topari'' je igbana to n sele pelu opo oksijini ti ko ni adapo alegbogi (chemical compound) tikojona. O soro gidi lati ni igbona topari nitoripe ko si ona kankan ti adapo alegbogi tikojona ko ni wa.
 
* ''Igbana tabi ijona tikopari'' n sele ti opoiye oksijini to wa fun lilo ko to ninu ifesi alegbogi ohun. O si se e se ki iye oksijini toto o wa sugbon ona ti ijona na n sele ko gba laaye ki gbogbo oksijini ibe o se e lo.
 
{{ekunrere}}
 
== Itokasi ==
{{reflist}}
 
 
[[Ẹ̀ka:Kẹ́místrì]]
Line 42 ⟶ 41:
[[it:Combustione]]
[[ja:燃焼]]
[[kn:ದಹಿಸುವಿಕೆ/ಉಷ್ಣ ವಿಕಸನ]]
[[ko:연소]]
[[lt:Degimo reakcija]]
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ìgbaná"