Akin Euba: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
New page: Akin Euba Joshua Uzoigwe (1992), Akin Euba: An Introduction to the Life and Music of a Nigerian Composer (Bayreuth African Studies Series 25). Bayreuth: Eckhard Beitinger. ISBN: 3-927...
 
No edit summary
Ìlà 1:
[[AkinEwi EubaAyaba]]
 
ÌLÀNÀ ÌGBÉKALÈ EWÌ AYABA LÁÀRIN ÀWON ÒYÓ ÒSUN
Joshua Uzoigwe (1992), Akin Euba: An Introduction to the Life and Music of a Nigerian Composer (Bayreuth African Studies Series 25). Bayreuth: Eckhard Beitinger. ISBN: 3-927510-16-5; ISSN: 0178-0034. Oju-iwe = 109.
 
Gégé bí gbogbo ewì alohùn Yorùbá yòókù se ní ìlànà ìgbékalè tiwon, béè náà ni ewì ayaba se ni tirè. Òtító ní pé ìpète àti ìpèrò ewì alohùn wà nínú opolo apohùn, síbè a rí i pé kò sí bí apohùn kan se le jogún èyà ewì alohùn kan tó, tí kò ní ti fi ìgbà kan kó ìlànà ìgbékalè irú ewì béè tó jogún lówó òbí tàbí lówó ìran rè. Lára ìlànà ìgbékalè ewì alohùn láwùjo Yorùbá ni a ti rí ìmúrasílè. Ìmúrasílè yìí ni àkókó nínú ìlànà ìgbékalè ewì alohùn. Kó tó di pé àwon apohùn bó sí ojú agbo ìsèré ni wón ti kókó máa ń se imúrasílè ní ìkòkò. Ohun tí Ilésanmí (1990:96) so ni pé:
Ise Akin Euba ni onkowe ye wo ninu ise re yii. Loooto, ilana awon nGeesi ni Akin Euba fi n korin sugbon asa awon Yoruba ni o gbe ise re ka. Onkowe yii soro nipa iwadii ti Akin Euba se lori ilu. Onkowe yii ko saipin orin si isori. Gbogbo eni ti o ba ni nnkan se pelu tilutifon (music) ni iwe yii yoo wulo fun.
 
Ìmúrasílè se pàtàkì fún àwon apohùn ilè Yorùbá kí ó tó di ojó tí wón máa gbé e jáde sí gbangba. Ara ìmúrasílè ni kí akéwì; èyí-ówù-ó jé, mo irúfé aso tó lè bá ewì tó fé ké mu. Nítorí pé, ó ní bí akéwì ìbílè Yorùbá se máa ń múra lónà tí yóò fi gbayì lójú agbo ìsèré rè. Kò bójúmu pé kí apèsà, asùnjálá tàbí asunlámò so táì mórùn wojú agbo ìsèré. Ohun tó ye wón ni aso tòkètilè Yorùbá pèlú fìlà tàbí gèlè tó bójúmu, tàbí aso mìíràn tó je mó irú aré tí wón fé se.
 
A fara mó ohun tí Ilésanmí so yìí, sùgbón a fé se afikún pé kìí se aso tí àwon apohùn ewì alohùn gbódò máa wo lójú agbo ìsèré nìkan ló ye kó jé dandan. Ohun tí a ní lókàn ni pé lára ìmúrasílè ni kí akéwì tàbí apohùn yòówù tó jé mo bí ewì won yó se lo. Ìdí tí a fi so báyìí ni pé ewì alohùn kòòkan ló ni ìlànà ìgbékalè tirè. Àpeere ni pé ìlànà sísun ekún ìyàwó kò bá ti orin aremo mu, béè sì ni pé ìlànà sísun rárà yàtò sí ti ìjálá ògún, Ìyèrè Ifá àti béè béè lo. Àdáyébá ni gbogbo ìlànà ohùn yìí ní tòótó, ìlànà ìgbékalè òkòòkan kò sì yí padà gégé bí a se mo wón láti ìbèrè ojó. Àpeere ni pé ìlànà bí àwon apohùn se ń sun ìjálá láti ogún odún títí di òní yìí kò yí padà rárá. Ohun mìíràn tí a tún rí ni pé ìlànà ìgbékalè èyà lítírésò alohùn tí apohùn bá fé gbé kalè gbódò ti wò ó lára, kó sì ti di bárakú fún un láì máa fi epo bo iyò lójú agbo. Bákan náà, ìmúrasílè gbódò tun ti wa lórí irú ohun èlò bí i ìlù àti ìfon tó bá àgbékalè ewì béè mu. Àwon apohùn gbódò tún ti wà ní ìmúrasílè lórí bó se ye kí ojú agbo ìsèré wón rí.
 
Irúfé ìmúrasílè báwònyí ni a fé se àlàyé lé lórí nínú ìgbékale ewì ayaba láàrin àwon Òyó-Òsun. A rí i pé àwon ayaba náà ni ìlànà ìgbékalè ewì tiwon láwùjo. Won kì í sàdéédé ré èékánná lójó àjò. Ìwádìí lórí isé yìí jé kí á mò pé àwon àgbàlagbà ayaba ni wón sábà máa ń ní ìmò àti èbùn tó jinlè púpò nínú ìgbékalè ewì ayaba. Ìrírí àwon ayaba àgbà tó jinlè nínú ìgbé-ayé inú ààfin oba ló jé kó rí béè. Gbogbo àwon ayaba kéékèèké ni a gbó pé wón máa ń wá ààyè láti lo kó nípa ìlànà ìgbékalè ewì won lódò àwon ayaba àgbà. Èyí dàbí ìgbà tí olómoge tó ń lo sí ilé oko jáde láti kó bí yó se sun ekún ìyàwó.
 
Ònà mìíràn tí àwon ayaba tún máa ń gbá kó nípa ewì yìí ni pé lópò ìgbà, àwon ayaba kéékèèké a maa fi òrò sí àwon ayaba àgbà lénu láti síde ewì won. Nípa irú ìlànà yìí, a rí i pé òrò àwon ayaba kéékèèké dàbí òrò Yorùbá kan tó wí pé “orin tí èlúkú bá dá l’omo rè ń gbè”. Nínú ìlànà fífi òrò sí àwon ayaba àgbà lénu báyìí, ni àwon ayaba kéékèèké se máa ń ní ìmò tó jinlè nínú àgbéjáde ewì won.
 
Lópò ìgbà, isé àwon ayaba kéékèèké yìí náà se pàtàkì lójú agbo ewì won. Ìdí ni pé àwon ni elégbè nínú ewì won. Àwon náà a sì tún máa dá ewì sí àwon ayaba àgbà lénu, láàyè kan. Ní ìgbàkúùgbà tí àwon ayaba àgbà náà bá fé máa gbàgbé àwon ewì won kan. Òpò nínú àwon ayaba kéékèèké wònyìí gan-an ti gba ìmò tó jinlè lénu àwon ayaba àgbà télètélè ló fi rí béè. Àkíyèsí yìí jé kí á gbà pé wonú-wòde ni àwon ayaba àgbà àti ayaba kéékèèké máa ń se àgbékalè ewì won. Ohun tí à ń so ni pé lásìkò tí apá kan bá ń gbé ewì jáde lénu, ní sisè-n-tèlé ni apá kejì yóò máa gbè é.
 
Èyí kò pin síbè rárá, nínú àgbékalè ewì ayaba, àwon kì í kókó dá ewì jo bí i ti àwon apohùn kan. Èyí tí òkòòkan won bá mò, tó sì rántí ni wón máa ń gbé jáde lénu, tí àwon yòókù náà yóò sì jò máa wí ohun tí eni náà bá ń wí lápapò.
 
Òpò nínú àwon ewì ayaba ló tún jé àdáse. Enìkan soso ló máa ń gbé irú ewì yìí dúró. Eni tí ìmò re bá jinlè, yálà nínú ayaba àgbà tàbí láàrin ayaba kéékèèké ló máa ń dá gbé irú ewì yìí kalè. Lásìkò ti eni náà bá ń gbé irú ewì àdáse béè kalè, enu re ni àwon yòókù yóò sì máa wò. Irú ewì báyìí le jé oríkì oba, ìtàn oba, ìrísí oba tàbí ìwà oba ló ń gbé síta. Nínú irú ìlànà ìgbékalè ewì yìí, ààyè a tún sábà máa wà fún àwon ayaba yòókù láti segbe orin ewì náà ní ìparí. Ohun tí à ń so ni pé bí ewì yìí ti máa ń jé àdáse tó, síbè àwon kan a máa fi orin parí rè. Irú orin yìí nìkan ni àwon yòókù yóò sì jo ko papò ní Ìkádìí ewì ayaba báyìí.
Lópò ìgbà, àwon ayaba a máa jo pa àtéwó papò sí ewì won. A tún se àkíyèsí pé àwon ayaba a máa kó ara won ní ìjánu nínú àgbékalè ewì won. Ohun tí à ń so ni pé wón mo ibi tó ye kí wón ti dá enu dúró, wón mo ibi tó ye kí wón ti sègbè orin, wón mo ojú, wón sì mo ara. Bí won bá ti wo ojú ara won, wón ti mo ohun tó ye kí won ó se nínú ìgbékalè ewì won, yálà bóyá kí wón máa bá ewì won lo tàbí kí won dénudúró.
 
Lára ìlànà ìgbékalè ewì ayaba ni ìmúra ayaba wa. Láti ayébáyé wá, a gbó pé ìmúra àwon ayaba a máa fi ipò won hàn láwùjo. Kò sí eni tó máa rí ìmúra ayaba, tí kò ní tètè mò pé ayaba ni òun rí lágbo. Òsó olówó iyebíye tí won máa ń kó sí ara ni kí á so ni tàbí ti aso ńlá tí wón máa ń wò sí ara.
Lára aso tí àwon ayaba máa ń wò lágbo ni òfì, àdìre, Sányán, àlàárì àti béè béè lo. Mùgbè-mugbe ni àwon ayaba máa ń dá aso wònyìí sórùn láyé àtijó. Bóyá ìdí nìyí tí àwon Yorùbá se máa ń so pé “àrókanlè laso ayaba, àwòkanlè ni ti yàrà”. Gbólóhùn yìí fi hàn pé àwon ayaba kìí dá aso won ní péńpé bí aso esinsin. Gégé bí i aya olówó ni wón se máa ń dá aso tiwon. Bí wón bá tún wo aso tó gbayì báyìí tán, àwon a tún máa lo èsó bí i ìlèkè iyùn, lágídígba àti àkún. Béè tún ni pé; won a máa se òsó alára-n-barà mó irun orí won láyé àtijó. Bákan náà, bàtà tí wón máa ń wo sí esè a máa bá aso ara won mu. Gèlè orí won náà a sì tún máa bá aso ara won mu. Ní pàtàkì, wámú-wámú ni ìmúra àwon ayaba máa ń gún régé.
 
Òpòlopò ohun tí a so nípa ìmúra àwon ayaba wònyìí ni a rí pé òlàjú ti ń kó dànù lóde òní. Ìrísí àti ìmúra àwon ayaba òde òní kò fi béè gbayì tó ti ayé àtijó mó. Ìwádìí lórí isé yìí jé kí a mò pé ìdí tí òsó ara àwon ayaba fi máa ń lárinrin tó báyìí láyé àtijó ni pé won kì í sábà gbé ewì won kojá inú ààfin. Àyàfi tí a bá dé inú ààfin oba nìkan ni a tó le rí àwon ayaba wò bí i ìran. Won kì í sàdèédé rí won wò nígba náà gan-an, àyàfi ìgbà tí oba tuntun bá ń gorí ìté nìkan.
 
Irú aso tí a le bá lára àwon ayaba lóde òní kò kojá aso ànkóò bí i léèsì ìgbàlódé, ànkárá tàbí gínnì. Awon ayaba kan a sì tún máa lo ìlèkè iyùn àti àkún owó láti fi dá won mò. Lára ìmúra àwon ayaba òde òní ni ìrùkèrè tí wón máa ń mú lówó wà.
 
Ní tòótó, a kò fi ojú rí irú ìrùkèrè tí wón máa ń lò lásìkò ìwádìí isé yìí. Èyí kò jé kí a mò bóyá dúdú tàbí funfun ni. Ìwádìí tí a se ló jé kí á mò béè. Bi ó tilè jé pé a ti so saájú pé àwon ayaba a máa mú ìrùkèrè lówó, síbè a gbó pé kì í se gbogbo won ló ń mú ìrùkèrè lówó. Àwon ayaba àgbà nìkan ló máa ń mú ìrùkèrè lówó. Ohun tí a gbó ni pé ìrùkèrè tí àwon ayaba àgbà ń mú lówó nínú ìgbékalè ewì won yìí jé ti oko won tó ti wàjà. Àgbéjó ni a sì gbó pé wón máa ń gbé ìrùkèrè owó won náà jó lásìkò tí wón bá ń gbé ewì won kalè.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Akin_Euba"