Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Nnamdi Azikiwe"

23 bytes added ,  12:52, 15 Oṣù Kẹta 2008
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
[[Image:zik.jpg|thumb|right|Nnamdi Azikiwe]]
Ologbe '''Nnamdi Azikiwe''' (November 16, 1904 – May 11, 1996) je omo orile ede [[Naijiria]], lati [[eya]] [[Omo Igbo|Igbo]] ni apa ila orun ile [[Naijiria]]. Okan ninu awon [[oloselu]] pataki ni Azikwe je ni Naijiria. Azikwe je Aare (President) akoko fun orile ede Naijiria leyin igbati Naijiria gba ominira ni odun [[1960]].
A bí i ní odún 1904. Ó kàwé ní calabar àti Èkó. Òun ni olóòtu, Morning Post West African Pilot. Ó di ènìyàn dúdú àkókó tí yóò je Governor-General Nigeria ní 1960. Ó se ìdásílè University of Nsukka. Ó kú ní odún 1996.
 
 
{{ekunrere}}
[[Category:Ìgbésíayé]]