DNA: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 2:
'''DNA''' duro fun ''Deoxyribonucleic acid'' ni [[ede geesi]], eyi tumosi '''kikan deoksiribonukleu'''. DNA je [[nucleic acid|kikan nukleu]] ti o ni awon ilana [[genetics|abimo]] ti a n lo fun [[biological development|idagbasoke alaaye]] gbogbo awon iru [[cell (biology)|ahamo]] [[life|emi]]. Lamolara, DNA je [[double helix|alolara eleemeji]]. Awon apa DNA to ungbe awon ilana wonyi ni a unpe ni [[gene|abimo]], sugbon awon itelentele DNA miran wa fun idimule, tabi won wa fun iseeseese ilo ilana abimo yi. Lapapo mo [[RNA]] ati awon [[proteins|amoralokun]], DNA je ikan ninu awon [[macromolecules|horogbangba]] pataki meta to se koko fun gbogbo irun ohun elemi.
 
DNA ni awon [[polymers|alarapupo]] gigun meji awon eyo kekere kan ton je [[nucleotide|nukleotidi]], pelu [[backbone chain|igbaeyin]] to je adipo [[Monosaccharide|suga]] ati [[phosphate|oniyofosforu]] ti won je sisopapao pelu awon ide [[ester|esteri]]. Awon igunatinrin mejeji yi jo doju de ona odi si ara won bi be won je [[antiparallel (biochemistry)|alaifarajoolodiajodojuko]]. Awon ihun jije lilemo suga kookan ni ikan ninu awon iru horo merin tounje [[nucleobases|ipilenukleu]] (lasan bi, ''awon ipile''). [[Nucleic acid sequence|Itelentele]] awon ipilenukleu mererin yi leba igbaeyin ni won un samioro iwifun. Iwifun yi je kika pelu lilo [[genetic code|amioro alabimo]], to utokasi itelentele awon [[amino acid|kikan amino]] ninu awon proteini. Amioro na je kika nipa sise àwòkọ awon ìnà DNA si inu kikan nukleiki RNA to baramu nnu igbese kan to unje [[transcription (genetics)|isawoko]].
 
Ninu awon ahamo DNA je gbigbajo si idimu gigun kan to unje [[chromosome|kromosomu]]. Nigba [[cell division|ipin ahamo]] awon kromosomu yi je didameji ninu igbese [[DNA replication|itunda DNA]], to si unpese fun ahamo kookan awon kromosomu pipe tikookan fun won. [[Eukaryote|Awon agbarajo eukarioti]] (awon [[animal|eranko]], [[plant|ogbin]], [[Fungus|ehu]], ati [[protist|protisti]]) ko opo awon DNA won pamo sinu [[cell nucleus|nukleu ahamo]] ati awon DNA won miran sinu awon [[organelle|organeli]], bi [[mitochondria|mitokondria]] tabi [[chloroplasts|adawo-ewe]].<ref>{{cite book | last = Russell | first = Peter | title = iGenetics | publisher = Benjamin Cummings | location = New York | year = 2001 | isbn = 0-8053-4553-1 }}</ref> Lafiwe si awon [[prokaryote|prokarioti]] ([[bacteria|bakteria]] ati [[archaea|arkea]]) ti won unko DNA won pamo sinu [[cytoplasm|idanuahamo]] nikan. Ninu awon kromosomu, awo proteini [[chromatin|kromatini]] bi [[histone|histonu]] undipo o si unsegbajo DNA. Awon idimu idipo yi unselana ibasepo larin DNA ati awon proteini miran, nigba tounsejanu awon apa DNA wo ni yio sawoko.
Ìlà 14:
Ninu awon agbarajo alaye DNA ki saba wa bi horo kan soso, sugbon bi awon horo meji ti won je didimupo ni lilelile.<ref name=FWPUB>{{cite journal| author = Watson J.D. and Crick F.H.C. | pmid=13054692 | doi = 10.1038/171737a0 | url= http://www.nature.com/nature/dna50/watsoncrick.pdf | title=Ìdìmú kan fún Kíkan Núkléù Deọksiríbósì | journal=Nature | volume=171 | pages=737–738 | year=1953 | accessdate=4 May 2009|format=PDF| issue = 4356 | bibcode=1953Natur.171..737W}}</ref><ref name=berg>Berg J., Tymoczko J. and Stryer L. (2002) ''Biochemistry.'' W. H. Freeman and Company ISBN 0-7167-4955-6</ref> Awon mejeji lorapo bi eka igi, won ri bi [[double helix|alopo emeji]]. Awon nukleotidi atun ni apa igbaeyin horo, to mu ẹ̀wọ̀n na papo, ati ipilenukleu kan, to se basepo mo atinrin DNA miran ninu alopo na. Ipilenukleu kan to so po mo suga kan lo nje [[nucleoside|nukleosidi]] be sini ipile kan to so mo suga kan ati mo ikan tabi opo adipo oniyofosforu lo nje [[nucleotide|nukleotidi]]. Awon alarapupo ti won ni opo nukleotidi ti wo so po mo ara won (bi tinu DNA) lo nje [[polynucleotide|nukleotidipupo]].<ref name=IUPAC>[http://www.chem.qmul.ac.uk/iupac/misc/naabb.html Abbreviations and Symbols for Nucleic Acids, Polynucleotides and their Constituents] IUPAC-IUB Commission on Biochemical Nomenclature (CBN). Retrieved 03 January 2006.</ref>
 
Igbaeyin atinrin DNA je dida lati ibi awon ìṣẹ́kù [[phosphate|oniyofosforu]] ati [[carbohydrate|suga]].<ref name=Ghosh>{{cite journal |author=Ghosh A, Bansal M |title=A glossary of DNA structures from A to Z |journal=Acta Crystallogr D |volume=59 |issue=4 |pages=620–6 |year=2003 |pmid=12657780 |doi=10.1107/S0907444903003251}}</ref> Suga inu DNA ni [[deoxyribose|2-deoksiribosi]], to je suga [[pentose|pentosi]] ([[carbon|karbonu]]-marun). Awon suga na je sisopo latowo awon idipo oniyofosforu ti won da awon [[phosphodiester bond|ìdè fosfodiesteri]] larin awon s between the third and fifth carbon [[atom|atomu]] karbonu keta ati ikarun awon oruka suga itosi. Awon [[covalent bond|ide]] alaidogba yi tumosi pe atinrin DNA ni idojude. Ninu alopo emeji idojude awon nukleotidi ninu atinrin kan kojusi idojude won ninu atinrin keji: awon atinrin yi je the strands are ''antiparallelolodiajodojuko''. TheAwon asymmetricenu endsalaidogba ofawon DNAatinrin strandsDNA arelo callednje theenu [[directionality (molecular biology)|5′]] (''arun akoko/five prime'') andati [[directionality (molecular biology)|3′]] (''eta akoko/three prime'') ends, withpelu theenu 5' endto havingpari apelu terminaladipo phosphateoniyofosforu groupati and theenu 3' endto apari terminalpelu hydroxyladipo grouphaidroksi. OneIyato majorkan differencepataki betweent wa larin DNA andati RNA isni theiru sugar,suga withti thewon 2-deoxyribose inni, DNA beingni replacedsuga bypentosi the2-deoksiribosi alternativenigbati pentoseRNA sugarni suga pentosi [[ribose|ribosi]] in RNA.<ref name=berg/>
 
[[File:DNA orbit animated static thumb.png|thumb|upright|A section of DNA. The bases lie horizontally between the two spiraling strands.<ref>Created from [http://www.rcsb.org/pdb/cgi/explore.cgi?pdbId=1D65 PDB 1D65]</ref> Animated version at [[:File:DNA orbit animated.gif]].]]
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/DNA"