DNA: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 1:
[[Fáìlì:DNA123.png|thumb|right|150px|Aworan elegbemeta apere lilopo apa kan DNA]]
'''DNA''' duro fun ''Deoxyribonucleic acid'' ni [[ede geesi]], eyi tumosi '''deoksiribonúkléì kíkan''' (DNA tabi DNK). DNA je [[nucleic acid|núkléì kíkan]] ti o ni awon ilana [[genetics|abimo]] ti a n lo fun [[biological development|idagbasoke olounalàyè]] gbogbo awon iru [[cell (biology)|ahamo]] [[life|emi]]. Lamolara, DNA je [[double helix|alolara eleemeji]]. Awon apa DNA to ungbe awon ilana wonyi ni a unpe ni [[gene|abimo]], sugbon awon itelentele DNA miran wa fun idimule, tabi won wa fun iseeseese ilo ilana abimo yi. Lapapo mo [[RNA]] ati awon [[proteins|amoralokun]], DNA je ikan ninu awon [[macromolecules|horogbangba]] pataki meta to se koko fun gbogbo irun ohun elemi.
 
DNA ni awon [[polymers|alarapupo]] gigun meji awon eyo kekere kan ton je [[nucleotide|nukleotidi]], pelu [[backbone chain|igbaeyin]] to je adipo [[Monosaccharide|suga]] ati [[phosphate|oniyofosforu]] ti won je sisopapao pelu awon ide [[ester|esteri]]. Awon atinrin mejeji yi jo doju de ona odi si ara won bi be won je [[antiparallel (biochemistry)|olodiajodojuko]]. Awon ihun jije lilemo suga kookan ni ikan ninu awon iru horo merin tounje [[nucleobases|ipilenukleu]] (lasan bi, ''awon ipile''). [[Nucleic acid sequence|Itelentele]] awon ipilenukleu mererin yi leba igbaeyin ni won un samioro iwifun. Iwifun yi je kika pelu lilo [[genetic code|amioro alabimo]], to utokasi itelentele awon [[amino acid|kikan amino]] ninu awon proteini. Amioro na je kika nipa sise àwòkọ awon ìnà DNA si inu kikan nukleiki RNA to baramu nnu igbese kan to unje [[transcription (genetics)|isawoko]].
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/DNA"