Ìpínlẹ̀ Missouri: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
New page: Missouri Ipinle kan ni ile Amerika ni o n je Missouri. Aarin gbungbun iwo-oorun ile Amerika ni ipinle yii wa.. Oke kan ti o n je Ozark Mountain wa nibe. Ibe naa ni omi kan ti o n je M...
 
Category:Amerika
Ìlà 2:
 
Ipinle kan ni ile Amerika ni o n je Missouri. Aarin gbungbun iwo-oorun ile Amerika ni ipinle yii wa.. Oke kan ti o n je Ozark Mountain wa nibe. Ibe naa ni omi kan ti o n je Missouri wa. Apapo omi Missouri yii ati Mississippi ni odo ti o gun ju ni agbaye. Ile-ise po ni ipinle tii. Awon eniyan ti o n gbe ibe to 4,667,000. Jefferson City ni olu-ilu Missouri sugbon St. Louis ati Kasas City ni awon ilu ti o tobi ju nibe. Awon ile Faranse ni o gba Missouri 1673 ati 1682. Awon ile Amerika gba a ni 1803 o si di ipinle ni 1821. ninu ogun abel ile Amerika, awon Union ni Missouri ja fun.
 
 
[[Category:Amerika]]