Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Áljẹ́brà onígbọrọ"

k
robot Adding: bg:Линейна алгебра; cosmetic changes
k (robot Adding: bg:Линейна алгебра; cosmetic changes)
[[FileÀwòrán:Linear subspaces with shading.svg|thumb|250px|right|A line passing through the [[origin (mathematics)|origin]] (blue, thick) in [[Euclidean space|'''R'''<sup>3</sup>]] is a linear subspace, a common object of study in linear algebra.]]
 
'''Aljebra gbigboro''' (linear algebra) je eka imo isiro ti o ni se pelu imo nipa awon [[atokaona]] (vector), [[aaye atokaona]] (vector space), [[maapu gbigboro]] (linear map) ati awon [[ona-eto idogba gbigboro]] (system of linear equation). Aaye atokaona se pataki ninu imo isiro ayeodeoni, nipa bayi [[aljebra]] alatele wulo lopolopo ninu [[aljebra afoyemo]] ati [[agbeyewo alabase]] (functional analysis). O tun wulo gidigidi ninu awon [[sayensi aladabaye]] ati [[sayensi awujo]] nigba t'oje pe awon apere alainitele (nonlinear) se mu sunmo eyi to je alatele (linear).
 
== Ìtàn Áljẹ́brà gbigboro ==
Itan aljebra ayeodeoni bere ni arin odun 1843 ati 1844. Ni odun 1843, [[William Rowan Hamilton]] (eni ti o koko soro nipa ''atokaona'') se awari ''quaternions''. Ni odun 1844, [[Hermann Grassmann]] ko iwe ni ede [[Germani]] pelu akole ''Die lineale Ausdehnungslehre''. [[Arthur Cayley]] mu [[apotinomba]] (matrix) wa ni odun 1857. [[Ilana Cramer]] to n fihan wa bi a se le s'ojutu awon [[idogba iseyato abo]] (partial differential equation) lo so aljebra alatele di eko ti a n ko ni awon ile-eko giga. Fun apere, E.T. Copson ko pe:
 
:''Ni odun 1922 ti mo di oluko kekere ni ile-eko giga Edinburgh, o yamilenu lati ri pe ilanaeto eko yato si ti ile-eko giga Oxford. Eka bi [[isodiodidi Lebesgue]] (Lebesgue integration), [[ero apotinomba]] (matrix theory), [[agbeyewo aminomba]] (numerical analysis), [[alawonile Riemannian]] (Riemannian geometry), lori awon eyi ti n ko mo nkankan nipa won....'' E.T. Copson, Oro Isaju si ''Idogba Iseyato Abo'', 1973
 
[[CategoryẸ̀ka:Ìmọ̀ ìsirò]]
 
 
 
[[Category:Ìmọ̀ ìsirò]]
 
[[ar:جبر خطي]]
[[bg:Линейна алгебра]]
[[bn:রৈখিক বীজগণিত]]
[[bs:Linearna algebra]]
25,940

edits