Ààrùn ẹ̀dọ̀ A: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Created article
 
Mo ṣayipada ami ori ọrọ
 
Ìlà 19:
 
<!-- Prevention and Treatment -->
[[òògùn ààrùn ẹ̀dọ̀ A]] dára fún ìdẹ́kun.<ref name=AFP2012/><ref name=Irv2012>{{Cite journal | last1 = Irving | first1 = GJ. | last2 = Holden | first2 = J. | last3 = Yang | first3 = R. | last4 = Pope | first4 = D. | title = Hepatitis A immunisation in persons not previously exposed to hepatitis A. | journal = Cochrane Database Syst Rev | volume = 7 | issue = | pages = CD009051 | year = 2012 | doi = 10.1002/14651858.CD009051.pub2 | pmid = 22786522 }}</ref> Àwọn orílẹ̀ èdè kan fọwọ́si níwọ̀nba fún àwọn ọmọdé àti fún àwọn tí ó wà léwu gidi tí akòití fún ní oogùn rẹ.<ref name=AFP2012/><ref name=WHO2013/> Ó hàn pé ó dára fún ẹ̀mí.<ref name=AFP2012/> Àwọn ìwọ̀n ìdẹ́kun míìrán ni [[ọwọ́ fífọ̀]] àti síse oúnjẹ dáradára.<ref name=AFP2012/> Kòsí ìtọjú kan pàtó, pẹ̀lú ìsinmi àti àwọn oogùn fún [[ìṣu]] tàbí [[ṣíṣunú]] ni a fọwọ́sífọwọsí bí o ti yẹ lóòrekoorè.<ref name=AFP2012/> Àwọn àkóràn sábà maa ńlọ pátápátá láìsi àrùn ẹ̀dọ̀ rárá.<ref name=AFP2012/> Ìtọjú fún àrùn ẹ̀dọ̀ líle, bí ó bá wáyé, ni pẹ̀lú [[Ìrọ́pò ẹ̀dọ̀]].<ref name=AFP2012/>
 
<!-- Epidemiology -->