Akadianu: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Addbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 62 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q35518 (translate me)
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
Ìlà 3:
[[Akkadian]]
 
Èdè sèmítíìkìsẹ̀mítíìkì kan ni eléyìí tí wónwọ́n ń sosọ ní ilè Mesopotámà láàárín séńtúrùsẹ́ńtúrù 2300 sí 500 sáájú ìbí kírísítì (c2300 to c500). A tún máa ń pe èdè yìí ní Accadian. Ìgbà mìíràn a tún máa ń pè é ní Assyro-Babylonian. A mú orúkoorúkọ tí ó gbèyìn yìí láti ara àwonàwọn èkaẹ̀ka-èdè rèrẹ̀ méjèèjì (Assyrian àti Babylonian). Èdè yìí ni ó rópòrọ́pò Sumerian tí wónwọ́n ti ń sosọìpínlèìpínlẹ̀ yìí télètẹ́lẹ̀. ÈkaẸ̀ka-èdè Babylonian ni wónwọ́n ti ń lò gégégẹ́gẹ́ bí èdè ìfisejobíìfiṣejọbí (lingua france) láti ìbèrèìbẹ̀rẹ̀ pèpèpèpẹ̀ láti nnkannǹkan bíi mìléníònùmìlẹ́níọ̀nù kìíní sáájú ìbí kírísítì (1st millennium B.C) sùgbónṣùgbọ́n láàárín séńtúrìsẹ́ńtúrì díèdíẹ̀ èdè Aramaic ti gba ipò rèrẹ̀ síbèsíbẹ̀ Babylonian sì tì jéjẹ́ èdè tí wónwọ́n ń lò fún ìwé kíkokíkọ àti kíkà tí di mìléníònùmìléníọ̀nù kìíní léyìnlẹ́yìn ikú kírísítì (1st Millenium A.D). ÀkotóÀkọtọ́ kúnífóòmùkúnífọ́ọ̀mù (Cuineform script) ni wónwọ́n fi kokọ Akkadian sílèsílẹ̀. SéńtúrìSẹ́ńtúrì kokàndínlógúnkọkàndínlógún (19th century) ni wónwọ́n tú u palèpalẹ̀ (decipher) sí èdè tó yé tawo-tògbèrìtọ̀gbèrì.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Akadianu"