Ṣàngó: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
Ìlà 1:
'''Ṣàngó''' Olukoso, Oko Oya.
 
Ṣàngó Je Okan lara Awon Orisa ti awon yorùbá n bòbọ̀ wọ́a ni àjànàkú kojákọjá a morí nnkannǹkan fìrí, bí a bá rí erin, káwípe a rí erin ní òròòrọ̀ Ṣàngó jéjẹ́ láàárin àwon òrìsà ileeileẹ Yorùbá. Ṣàngó jéjẹ́ òrìsà takuntakun kan gbòógì láàárín àwon òrìsà tókù ní ilèe Yorùbá. Ó jéjẹ́ orisà tí ìran rèrẹ̀ kún fún ìbèrùìbẹ̀rù. Ìrísí, ìṣe àti ìsọ̀rọ̀ rẹ̀ pàápàá kún fún ìbèrùìbẹ̀rù nígbàtí ó wà laaye nítorípé ènìyàn la gbọ́ pé Ṣàngó jẹ́ télètẹ́lẹ̀ kí ó tó di òrìṣà àrá. Ìtàn sosọ wí pé omoọmọ ÒrányànỌ̀rányàn ni sàngóṣàngó i ṣe àti pé OyaỌya, ÒṣunỌ̀ṣun ati ObàỌbà jẹ́ ìyàwó rẹ̀.
 
Ìhùwàsí búburú ati dídá wàhalá ati ìkoluraìkọlura pèlúpẹ̀lú ìjayé fàmílétè-kí-n-tutótutọ́ pòpọ̀ lówólọ́wọ́ sàngóṣàngó gégég̣ẹ́gẹ́ObaỌba tó bẹ́ẹ̀ títí ó fi di òtéyímikáọ̀tẹ́yímiká, èyí jásí wí pé tọmọdé tàgbà dìtèdìtẹ̀ mómọ́ o. WónWọ́n fi ayé ni í lára. Ó sì fi ìlú ÒyóỌ̀yọ́ sílèsílẹ̀ nígbèyìnnígbẹ̀yìn-gbéyíngbẹ́yín. Ó pokùnso sí ìdí igi àyàn kan lébàlẹ́bà ònàọ̀nà nítòsí ÒyóỌ̀yọ́ nígbàtí OyaỌya: Ìyàwó rẹ̀ kan tókù náà sì di odò.
 
OgbónỌgbọ́nàwonàwọn ènìyàn sàngóṣàngó tókù dá láti fi bá àwonàwọn òtáọ̀tá rèrẹ̀ jà nípa títi iná bolébọlé wonwọn àti béèbéèbẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lolọ ni ó sosọ sàngóṣàngó di òrìṣà tí wọ́n ń bobọ títí dòní tí wónwọ́n sì ńfi enuẹnu wonwọn túúbá wí pé sàngóṣàngó kò so: ObaỌba koso.
 
ÀWONÀWỌN ORÚKOORÚKỌSÀNGÓṢÀNGÓ Ń JÉJẸ́
 
Oríṣiríṣi orúkoorúkọ ni a mọ sàngóṣàngó sí nínú èyí tí gbogbo wonwọn sì ní ìtumòìtumọ̀ tàbí ìdí kan pàtó ti a fi ńpè wọ́n béèbẹ́ẹ̀. ÀwonÀwọn orúkoorúkọ bíi ìwònyìíìwọ̀nyìí:
 
1. Olúkòso: Ẹnití a mòmọ̀ mọ́ kòso tàbí obaọba tí ó wolèwọlẹ̀ sí kòso.
 
2. ArèkújayéArẹ̀kújayé:
 
3. Àjàlájí:
 
4. Ayílègbe ÒrunỌ̀run:
 
5. Olójú Orógbó: nítorípé orógbó ni obì tirètirẹ̀, òun ni ó sì máa ń ṣàfééríṣàfẹ́ẹ́rí nígbà ayé rèrẹ̀. Orógbó náà sì ni a máa ń lo ní ojúboojúbọ sàngóṣàngó títí di òní.
 
6. Èbìtì-àlàpà-peku-tiyètiyètiyẹ̀tiyẹ̀: Òrìṣà tí ó máa ń fi ìbínú gbígbóná pa ènìyàn ni àpalàyà tàbí àpafòn.
 
7. Onibon òrunọ̀run: gégégẹ́gẹ́òrìsàòrìṣà ó ń mú kí àrá sán wá láti ojú òrunọ̀run pèlúpẹ̀lú ìrókèkèìrọ́kẹ̀kẹ̀ tó lágbára.
 
8. Jàkúta: gégégẹ́gẹ́ bí òrìṣà tí ń fi òkúta jà (edùnẹdùn àrá). Irúfẹ́ òkúta kékerékékẹrẹ́ kan tí ó máa sekúpa ènìyàn nípasẹ̀ sàngóṣàngó
 
9. AbotumoAbọtumọ-bí-owú: Òrìsà léè woléwọlé pa ènìyàn bi eniẹnierùẹrù ń lá ni ó wólu irú eniẹni bẹ́ẹ̀.
 
10. Èbìtì-káwó-pònyìn-soro: Irúfẹ́ Òrìṣà tí ó jẹ́ wí pé ìṣowóìṣọwọ́-sekúpa asebi rẹ̀ máa ńya ènìyàn lénulẹ́nu gidigidi.
 
11. Alágbára-inú-aféféafẹ́fẹ́: Òrìsà tí ó jéjẹ́ wípé owọ́jàọwọ́jà a rerẹ, máa ńwá láti inú aféféafẹ́fẹ́ tàbí òfurufú ni.
 
12. Abánjà-májẹ̀bi: òrìṣà tíí jà láì ṣègbè léyìnlẹ́yìn aṣebi tàbí ṣe àṣìmú elòmíràn fún oníṣéoníṣẹ́ ibi.
 
13. Lánníkú-okoọkọ-oyaọya: Òrìsà tí o ni èrùẹ̀rù iku níkàwóníkàwọ́.
 
14. ÒkokonkòÒkokoǹkò èbìtìẹ̀bìtì: Òrìsà tí ó le subú lu ènìyàn bii ìgànnán tí ó ti denukọlèdẹnukọlẹ̀.
 
15. EléèmòEléèmọ̀: Òrìsà tí ó ni èèmòèèmọ̀.
 
AWON IWE ITOKASIITỌKASI
 
1. Daramola Olu [1967] AwonAwọn Asa ati Orisa IleIlẹ Yoruba. Lati owoọwọ Olu Daramola ati
jẹjẹ Adebayọ
jeje Adebayo
 
2. Adeoye C. L. [1985] IgbagboIgbagbọ ati EsinẸsin Yorùbá. Ibadan. Evans Brother. Press
 
 
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ṣàngó"