Tíátà: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Addbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 121 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q11635 (translate me)
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
Ìlà 1:
[[Fáìlì:New York State Theater by David Shankbone.jpg|thumb|right|Gbangan Tiata]]
'''Tíátà''' jéjẹ́ òròọ̀rọ̀ tí ó wáyé lati inú [[èdè Gíríìkì]] tí o túmòtúmọ̀ sí ibì ìwòran ó sì tún ní èkaẹ̀ka bí eré ìtàgé tí ó túnmòtúnmọ̀ sí pé, nígbàtí ènìyàn kan tàbí jù béèbẹ́ẹ̀ bá kó ara wonwọn jojọ ní àkókò kan tábì sí ìbìkan láti dá àwonàwọn ènìyàn lárayá. Nípa ìtúmòìtúmọ̀ tí ó gbòòrò yí, lati ìgbà tí ènìyàn ti wà láyé ni tíátà ti wà to béèbẹ́ẹ̀ gegẹ ti ó se sajejuwe ìgbé ayé ènìyàn nítorí Ìfé àwonàwọn ènìyàn si ìtàn sísosísọ. Lati ipinlèsèipinlẹ̀ṣẹ̀ tíátà, ni ó ti nń mú orísiirísi àrà dání. A sì máa nńàwonàwọn èròjà bi òròọ̀rọ̀, ìsesíìṣesí, orin, ijóijọ́ àti ìwòran papòpapọ̀ mómọ́ eré ìtàgé sínú tíátà. Tíátà ayé ìsinsìnyí ni ó tún kún fún òtítoòtítọ bí ó tilétilẹ́ jéjẹ́ pé ó pín sí orísiirísioríṣiiríṣi ònàọ̀nà.
Tíátà àkókóàkọ́kọ́ ní a se ní ègberúnẹ̀gbẹrún odúnọdún méjì sájú ikú Olúwa wa séyìnsẹ́yìn, ni ó jéjẹ́ eré ìtara nípa ilèilẹ̀ Ígíbítì ìgbanì. Ìtàn nípa OlórunỌlọ́run órísírì ni wónwọ́n fi nń se tíátà ni ododúnọdọdún lati sin OlórunỌlọ́run ósírísì wonwọn yi títi di ìgbà yé òlàjúọ̀làjú, èyí wá fi hàn nípa ìbásepòìbásepọ̀ tí ó wa láàrín tíátà àti èsinẹ̀sin.
ÀwonÀwọn ará Gíríkì ìgbanì ni ó kókó seṣe àgbékalèàgbékalẹ̀ tíátà gégégẹ́gẹ́ìseìṣe, wónwọ́ntúnmòtúnmọ̀ tíátà sí orísiríoríṣirí ònàọ̀nà bí eré ti adùn kéyìnkẹ́yìn rèrẹ̀, eré ti ìbànújéìbànújẹ́ kéyìnkẹ́yìn rèrẹ̀ àti eré tí ó se àpèjúwe àwùjoàwùjọ.
SùgbónṢùgbọ́n láyé òde òní, tíátà síseṣíṣe ti gba ìgbà òtunọ̀tun, tí à nń se sínú fánrán fún àgbéléwò àwonàwọn ènìyàn fún ìgbádùn. Tíátà síseṣíṣe ti wá da iséiṣẹ́ òòjóòòjọ́ àwonàwọn kan lóde òní. Tíátà àsààṣà àti iseiṣeàwonàwọn òsèrè máa nń lò latí seṣe ìgbélékè àsààṣà àti ìseìṣe tí ó ti dòkú, pàápàá ní ilèilẹ̀ Áfíríkà. Nípa tíátà ni a ti mòmọ̀ pàápàá ni ilèilẹ̀ Yorùbá àwonàwọn àsààṣà ati iseiṣe wa, tí ó ti sonùsọnù nítorí àsààṣà àti ìwà àwonàwọn òyìnbó ti gba àsààṣà àti ìseìṣe wa lówólọ́wọ́ wa.
ÒkanỌ̀kan nínú ìsòríìṣọ̀rí tíátà ni, tíátà nípa àwùjoàwùjọ àti òsèlú. Tíátà nípa àwùjoàwùjọàwonàwọn eléré ìtàgé fi nń se òpòlópòọ̀pọ̀lópọ̀ àyípadà sí àwonàwọn àlébù àti kùdìèkùdìẹ̀-kudiekudiẹ tó kù nínú àwùjoàwùjọ wa lónìí. Nípà tíátà síseṣíṣe yálà nípa eré ìtàgé tàbí ti àgbéléwò ni àtúnseàtúnṣe ti nńòpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ ayé tí ó wà ní ìkòríta ìríjú, tí wonwọn kó si momọ ohun tó yeyẹ lati seṣe. ÒpòlopòỌ̀pọ̀lọpọ̀ olósèlú ni bá tí sosọ ayé di tàwontàwọn nìkan, bí kò bá sí ti àwonàwọn aléré ìtàgé tábì ti àgbéléwò tí óun pi ìwà ìbàjéìbàjẹ́ wonwọn léde.
Tíátà tí ó ti wà lati bí òpòọ̀pọ̀ odúnọdún séyìnṣẹ́yìn, ló ti gbá àtúnseàtúnṣe nípa ìdàgbàsókè tí ó ti dé báa ní ayé òde òní. Tíátà siseṣ̣iṣe yálà ti eré ìtàgé tàbí ti àgbéléwò ló wà fún èkóẹ̀kọ́, ìtósónàìtọ́sọ́nà ati fún ìsàtúnseìṣàtúnṣe àwùjoàwùjọ tí a wà lónìí.
 
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Tíátà"