Ẹ̀sìn Islam: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k →‎Ijapo lori Internet: removed deleted template, removed: {{Link FA|tr}} using AWB (11720)
No edit summary
Ìlà 98:
== IKETA : IHSAN<ref>Alye nipa Ihsaan [http://www.esinislam.com/Islamiyyat_Index/Arabic_English_Quran_Surah_Index.htm]</ref> ==
 
Eleyi tumo si pe ki ire Musulumi maa sin Olohun re pelu igbagbo ati esin ododo gegebi eni-wipe o n wo Olohun AdedaAdedaa lojukoroju, bayibi ni,o tile biotilejeje pe ire kori I dajudaju Oun n ri o. Bakanaa, ki o rii daju wipe oun se ohun kohun ni ibamu pelu ilana (Sunnah) ojise e Re; annabi Muhammad (ki ike ati ola Olohun ki o baa).
 
Bakan- naa ni ISLAM tun feto si igbesi aye awon eni ti o gba a lesin yala ni iwasi won ni eyo kookan ni o tabi nigbati won ba wa nijonijo ni ona ti oriire aye ati torun yo o fi je tiwon. Nitori idi eyi ni o fi se fife iyawo ni eto fun awon atele re ti o si se won lojukokoro lo sibe. O si se sina sise ati iwa pansaga ni eewo fun won ati awon isesi-i-laabi miran. Bee ni o si se dida ibi po ati sisaanu awon alaini ati talika ni oranyan pelu amojuto won. Gegebi o ti senilojukokoro lo si ibi gbogbo iwa to dara ti o si se e ni oranyan, bee gege ti o si kininilo nipa gbogbo iwa buruku ti o si se e ni eewo. Siwaju sii, o se kiko oro jo lona mimo gegebii owo sise tabi yiyafunnilo ati ohun ti o fara pe eleyii ni eto. Ni idakeji ewe, o se owo ele (riba) ati gbogbo owokowo ati ohun ti o ba ti ni modaru ati awuruju ninu ni eewo.