Shola Allyson: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Created by translating the page "Shola Allyson"
 
k corr using AWB
Ìlà 8:
 
== Ibere igbesi Aye re ati irin ajo eko re ==
Won bi Shola Allyson ni ilu [[Ìkòròdú|Ikorodu]], ni [[ipinle Eko]] ni ibere odun 1970. O lo si ile-iwe alakoobere Anglican , ti ilu [[Ìkòròdú|Ikorodu,]], leyin eyi ni o te siwaju ni ile-iwe Girama [[Ìkòròdú|Shams-el-deen]], ni ilu [[Ìkòròdú|Ikorod]] fun ipele eko eleekeji. Leyin eyi ni o lo si ile-iwe Gbogbonise  ti ijoba  (Technical College) ni [[Ikeja|Agidingbi]] [[Ikeja]], ni bi ti o ti ko nipa imo okowo  (Business Studies) ti o si gba iwe eri  (NBTE).<ref name="Solabio">{{Cite web|url=http://solaallyson.com/tours-events/biography/|title=Sola Allyson - Biography}}</ref>
 
Ni odun 1997, o wo ile-iwe Polytechnic, Ibadan ti o si ko nipa imo Ayinike Orin (Music Technology), ti o da lori bi a se n lo ohun ninu orin. Ibe ni o ti ni iwe eri (HND) Higher National Diploma pelu ipo ti o ga julo.<ref name="Solabio" /><ref name="The Nigerian Voice" />