Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): P: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
k corr using AWB
 
Ìlà 37:
pàdí, v.t. to be cracked at the bottom (said of pots, etc.) Ìkòkò náà pàdí. That pot is cracked.
 
pàdí, v.t. to be the cause of . Ǹjẹ́ o mọ ohun tí ó pàdí iná náà? (Do you know what caused the fire?).
 
pàdi, n. bunch of banana, etc. Ó ra pádi ọ̀gẹ̀dẹ̀ kan. (He bought a bunch of bananas.)
Ìlà 63:
pagbo, v.i to make or form a ring or circle, to arrange in a circle. Wọ́n pagbo They arranged themselves in a circle.
 
pahín payín, v.i to chip off two of the upper front teeth (for fashion), to file teeth. Ó pahín . He filed his teeth.
 
pahím keke, Payín keke, v.t. to gnash the teeth. Yóò máà pahín keke nígbà tí ó bá gbọ́ pé iṣẹ náà kò bó sí i mọ́. (He will be gnashing his teeth when he hears that he lost the contact.
Ìlà 73:
Pajápajá, n. numbness, cramp pajápajá mú un. (He has cramp.
 
pajẹ, v.t. to kill animal for food, to miss, to omit. ó pa á jẹ . (He killed it and ale it
 
pakà, v.t. to thresh corn. Ó pakà (He threshed corn.)
Ìlà 81:
pákáńleke, n. worry, compulsion, force. pákáńleke tí ó ń ṣe hàn lójú rẹ̀. (The worry showed on his face.
 
pa kànnàkánná, v.t. (of eyes) to be dazed with, blows, lighting, etc. Ojú rẹ̀ pa kànnàkánná . (He felt dazed.)
 
pakàpakà, Apakà, n. corn thresher, thresher of corn. pakàpakà ni (He is a corn thresher.)
Ìlà 132:
pààlà, v.t. to mark boundary of land or territory, to demarcate boundary between land or territory. A pààlà oko wa. (We demarcated the boundary between our farms.)
 
pàlà, adv. with much effort, with difficult, to writh in pain. Ó ń rá pàlà . (He is writhing in pain.)
 
palaba, adj. fist, broad, flat. Ẹ̀rẹ̀kẹ́ ọmọ náà rí palaba. (The boy has a glat cheek.)
Ìlà 159:
pa lára dà v.t. to transform, to change into another form. Ó ti pa á lára dà sí orísìí mìíràn. (He has changed it into another form.)
 
pa láró, v.t. to dye. Ó pa irun rẹ̀ láró sí dúdú nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ síí hewú . (She dyed her hair black when it began to book grey.)
 
pa láṣe v.t. to command, to order, to authorize. Ó pa á láṣẹ pé kí n rà á. (He ordered that I buy it.)
Ìlà 169:
palẹ̀ mọ́, v.t. to put things together or in order, to clear, to take away. Wọ́n palẹ̀ òkú náà mọ́ fún sínsin. (They took away the corpse for burial.)
 
pa lẹ́rìn-ín v.t. to make to laugh. Ó pa mí lẹ́rìn-ín . (He made me laugh.)
 
páálí, n. card-board
Ìlà 179:
pa lọ́lọ́, pa rọ́rọ́, v.i. to be quiet, still or motionless, to be awed, to be silent. Ó pa lọ́lọ́. (He remained silent.)
 
pa lọ́tí v.i. to be drunk, to swell up with pride. Ayọ̀ ń pa ọ́ lọ́tí . (You are drunk with success.)
 
pámi, v.i. to be disheartened, to lose heart.
Ìlà 187:
pa mọ́kùn, v.t. to keep in mind, to keep to oneself. Ó pa àṣíírí náà mọ̣́kùn (ara rẹ). (He kept the secret to him self.)
 
pa mọ́lẹ̀, v.t. to conceal, to hide, to suppress. A kò lè pa ìbínú rẹ̀ mọ́lẹ̀ . (We could not suppress her anger.)
 
paamọ́lẹ̀ paramọ́lẹ̀, n. viper, adder
Ìlà 205:
pánlún, pán-ún adv. at once, at a stroke. Ó kán an.
 
pan-hun pán, pọ́n-ún, pọ́n-hún, adv. at, once, at a stroke. Ö kán igi náà pọ́n-ún . (He broke the stick at once.)
 
pani pànìyàn, v.t. to kill to murder, to kill a person, to kill someone. Ó lè pani. (He can kill someone.)
 
panígbe, v.t. to cause to cry, to, make to cry. Ó pa á nígbe . (He made him cry.)
 
panígbè, v.t. to be severely, to worry, to trash. Ó pa á nígbè. (He trashed him.)
 
panilérìn-ín, adj amusing, exciting, laughter, ridiculous. Fìlà tí o dé panilẹ́rìn-ín . (You look ridiculous in the hat you put on.)
 
panipani, n. murder. Òṣèré náà kò ní ọgbọ́n panipani nínú. (The players lacked the killer instinct.)
Ìlà 267:
pa poro, v.i. to corrugate, to make a furrow. Ó pa poro. (He made a furrow.)
 
papọ̀, v.t. to join, to mingle together, to unite, to assemble. A papọ̀ . (We assembled.)
 
pàpọ̀ ju, v.i. to be abundant, to be numerous. A pàpọ̀ jù. (We were very numerous.)
Ìlà 273:
páraá. n. the upper part of the plate rests on the posts supporting a piazza.
 
pàrà, adv. with suddenness, at once, suddenly. Ó jágbè mọ́ mi pàrà . (He shouted at me suddenly.)
 
para, v.t. to rub the skin with ointment. Ó fi epo para. (He rubbed palm-oil on his body.)
Ìlà 355:
patì, v.t. to keep on one side, to neglect, to shelve, to ignore. Ó pa á tì. (He ignored him.)
 
pàtì, adv. forcibly, violently Ó fi eyín já ẹran pàtì . (He forcibly bit some meat.)
 
pàtìpàtì, adv. forcibly, violently, doggedly, Ó ń jà pàtìpàtì . (He is fighting doggedly.)
 
pátipàti adj. shabby, to be covered in weals Are wọ́n rí pátipàti (Their bodies were covered in weals.)
 
patiyẹ, n. whip, cane. Ó n ọmọ náà ní patiyẹ . (He hit the child with a cane.)
 
pàtó adv. exactly, definitely, gist of a metter. Sọ fún mi ní pàtó ohun tí ó sọ. (Tell me the gist of what he said.)
Ìlà 423:
Pilẹ̀, Pilẹ̀ṣẹ̀, v.t. to commence to begin, to originate. Òun ló pilẹ̀ rẹ (He began it)
 
Pìmọ̀, Pìmọ̀ Pọ̀, v.i. to take counsel together. Wọ́n pìmọ̀ pọ̀ . (They took counsel together)
 
Pín, v.t. to divide, to share, to distribute to allot. A pín in sí méjì (We divided it into two)
Ìlà 479:
Pípé, adj. long, durable, old, ancient. Ọjọ́ pípẹ́ ni ó gbà á kí ó tó parí rẹ̀ (He took him a long time to complete it)
 
Pípẹ́ títí, n. long duration . Iṣẹ́ ọlọ́jọ́ pípẹ́ títí ni (It was a contract of a long duration)
 
Pínpín, n. division, sharing