Ìyìnbọn mọ́ ọ̀pọ̀ ènìyàn ní ṣọ́ọ̀sì ní Charleston: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
k corr using AWB
Ìlà 6:
| coordinates = {{coord|32|47|15|N|79|55|59|W}}
}}|map_size=|map_alt=Charleston, South Carolina|map_caption=|location=[[Emanuel African Methodist Episcopal Church]]<br />[[Charleston, South Carolina]], U.S.|target=[[African American]] churchgoers|coordinates={{Coord|32|47|15|N|79|55|59|W|display=inline,title}}|date={{start date|2015|06|17}}|time={{circa}} 9:05 p.m. &ndash; c. 9:11 p.m.<ref name="ABC.Documents">{{cite web|url=http://abcnews.go.com/US/police-documents-reveal-deadly-minutes-inside-south-carolina/story?id=34836336|title=New Police Documents Reveal Deadly Minutes Inside South Carolina Church|publisher=ABC News|date=October 29, 2015|accessdate=December 28, 2015}}</ref>|timezone=[[Eastern Daylight Time|EDT]]|type=[[Mass shooting]]<ref name="WashingtonPost-Shooting-2015">{{cite news|last1=Bever|first1=Lindsey|last2=Costa|first2=Robert|title=9 dead in shooting at historic Charleston African American church. Police chief calls it ‘hate crime.’|url=https://www.washingtonpost.com/news/morning-mix/wp/2015/06/17/white-gunman-sought-in-shooting-at-historic-charleston-african-ame-church/|accessdate=June 18, 2015|work=[[The Washington Post]]|date=June 17, 2015}}</ref><br />[[Hate crime]]<br />|fatalities=9<ref name="WashingtonPost-Shooting-2015" /><ref name="MyFox8-RoofConfesses-2015">{{cite web|url=http://myfox8.com/2015/06/19/charleston-shooting-suspect-dylan-roof-confesses-to-killing-9-people/|title=Dylann Roof confesses to killing 9 people in Charleston church, wanting to start 'race war'|publisher=[[WGHP]]|date=June 19, 2015|accessdate=June 19, 2015}}</ref>|injuries=1<ref name="DailyMirror-CharlestonChurch-2015">{{cite web|url=https://www.mirror.co.uk/news/world-news/charleston-church-shooting-first-picture-5904803|title=Charleston church shooting: First picture of 'gunman' on the run after nine people shot dead|work=[[Daily Mirror]]|date=June 18, 2015|accessdate=June 18, 2015}}</ref>|perp=[[Dylann Roof]] (sentenced to death)<ref name="Telegraph-RoofConfesses-2015">{{cite web|url=https://www.telegraph.co.uk/news/worldnews/northamerica/usa/11686370/Dylann-Roof-confesses-to-Charleston-shooting-as-governer-calls-for-death-penalty.html|title=Dylann Roof confesses to Charleston shooting as governor calls for death penalty|work=[[The Daily Telegraph]]|date=June 19, 2015|accessdate=June 19, 2015|first=Andrew|last=Marszal}}</ref>|weapons=[[Glock 41]] [[.45 ACP|.45-caliber]] [[handgun]]|numparts=<!-- or | numpart = -->|dfens=<!-- or | dfen = -->|motive=[[White supremacy]], desire to start a [[race war]]|website=<!-- URL|example.com}} -->}}
'''Ìyìnbọn mọ́ ọ̀pọ̀ ènìyàn ní ṣọ́ọ̀sì ní Charleston''' (tí a tún mọ̀ bi '''Ìfikúparun ṣọ́ọ̀sì ní Charleston)''' <ref>{{Cite web}}</ref> <ref>{{Cite web}}</ref> <ref>{{Cite web}}</ref> jẹ́ ìṣẹ́lẹ̀ ìfìbọn pa ọ̀pọ̀ èníyàn tó ṣẹlẹ̀ nígbàtí [[Dylann Roof]], tó jẹ́ [[Ìṣègbéraga àwọn aláwọ̀funfun|oníṣègbéraga àwọn aláwọ̀funfun]] ọmọ ọdún 21 fìbọn pa àwọn aláwọ̀dúdú ará Amẹ́ríkà mẹ́sàn (tí olùṣọ́-àgùtàn àgbà àti, alàgbà ilé aṣòfin [[Clementa C. Pinckney]] wà nínú wọn) nígbà tí wọ́n únṣe ìsìn àdúrà nínú [[Ṣọ́ọ̀ṣì Emanuel African Methodist Episcopal]] ni ilu [[Charleston, South Carolina]], ni ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ 17 oṣù kẹrin, ọdún 2015. Awọn mẹ́ta péré ló yè nínú àwọn tó yìnbọn mọ́. Ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì tó ṣe iṣẹ́ ibi rẹ̀ tán, àwọn ọlọ́ọ̀pá gbá Roof mú ní Shelby, North Carolina . Roof jẹ́wọ́ iṣẹ́ ibi tó ṣe nírètí pé yíò fa ogun ẹlẹ́yàmẹ̀yà wá. Ṣọ́ọ̀ṣì tí Roof ti lọ pa àwọn ènìyàn ló jẹ́ ìkan núnú àwọn ṣọ́ọ̀ṣì aláwọ̀dúdú tó dàgbàjùlọ ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, tó jẹ́ ibùdó fún àgbájọ àwùjọ nípa [[àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú]] .
 
Wọ́n pinu pé Roof le dúró fún ìgbẹ́jọ́ ní ilé-ẹjọ́ ìjọba àpapọ̀, ni Oṣù Kejìlá ọdún 2016 wọ́n dá Roof lẹ́bi ẹ̀sùn 33 tí wọ́n jẹ́ ọ̀ran ikorira lábẹ́ ìjọba àpapọ̀ àti ẹ̀sùn ìpànìyàn tó ṣe pẹ̀lu ìyìnbọn náà. Ní ọjọ́ 10 Oṣù Kínní, ọdún 2017, wọ́n [[Ìdáẹjọ́ ikú látọwọ́ ìjọba àpapọ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà|dá ẹjọ́ iku]] fun. <ref name="jury-dylann-roof-death-penalty">{{Cite news|url=http://www.cnn.com/2017/01/11/us/dylann-roof-sentencing/|publisher=CNN|title=Victim's dad warns Dylann Roof: 'Your creator ... he's coming for you'|accessdate=April 14, 2017|date=January 11, 2017}}</ref> Lọ́tọ̀ Roof ní ẹ̀sùn ọ̀ràn ìpànìyàn mẹ́sàn ní [[Ilé-ẹjọ́ ìpínlẹ̀ (orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà)|ilé-ẹjọ́ ìpínlẹ̀]] South Carolina. Ní Oṣù Kẹrin ọdun 2017, Roof gbà pé òhun jẹ̀bi ẹ̀sùn mẹ́sẹ̀ẹ̀sán tí ìjọba ìpínlẹ̀ fi kan kó le baà yẹra fún ìdájọ́ ikú kejì, nítoríẹ̀ wọ́n dá ẹjọ́ [[ìjùṣẹ̀wọ́n ayérayé]] fún, fún ìkọ̀ọ̀kan àwọn ẹ̀sùn náà, èyí sínà fún ìjọba àpapọ̀ láti pàṣẹ ikú rẹ̀ nígbà tọ́ bá yá. <ref>{{Cite web}}</ref> <ref>{{Cite web}}</ref>
 
Roof fìgbàgbọ́ rẹ̀ hàn nípa [[ìkóríra ẹlẹ́yàmẹ̀yà]] nínú [[manifẹ́stò]] tó kọ sórí internet kó tó lọ yìnbọn pa àwọn ènìyàn lọ́jọ́ náà, àti nínú ìwé-ìṣẹ̀lẹ̀ tó kọ ní túbú lẹ́yín náà. ẹlẹ ṣaaju ki ibon naa, ati akọsilẹ kan ti a kọ lati ile-ẹhin lẹhinna. Awọn aworan ti a fi sori aaye ayelujara fihan Ọṣọ ti o nmu pẹlu awọn ami-ami ti o ni nkan ṣe pẹlu itẹsiwaju funfun ati pẹlu awọn fọto ti Flag of Confederate . Ibon yiyan ni ijiroro lori ifarahan onibara rẹ, ati tẹle awọn ibon yiyan, South Carolina Gbogbogbo Apejọ dibo lati yọ awọn Flag lati Ipinle Capitol ilẹ.
 
=== Awọn tó fikú dá lóró ===
Awọn tó fikú dá lóró jẹ́ mẹ́sàn, obìnrin mẹ́fà àti okùjrin mẹ́ta tí gbogbo wọ́n jẹ́ ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà ìjọ Methodist . Àwọn mẹ́jọ ku lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ níbẹ̀; ẹni kẹsan, Daniel Simmons, ku ni MUSC Medical Centre . <ref>{{Cite news|title=Former Mount Pleasant pastor among those slain|url=http://www.postandcourier.com/article/20150618/PC16/150619340/1177/daniel-l-simmons-74|work=The Post and Courier|date=June 19, 2015|accessdate=June 22, 2015}}</ref> Gbogbo wọn kú pa nipasẹ ọpọlọpọ awọn ibon gunshots ti firanṣẹ ni sunmọ ibiti o. <ref name="WashingtonPost-SuspectCaptured-2015">{{Cite web}}</ref> <ref name="RawEmotion">{{Cite web}}</ref> Awọn eniyan marun ti o ye ni ihamọ ti ko ni agbara, pẹlu Felicia Sanders, iya ti o ti pa lẹgbẹ Tywanza Sanders, ati ọmọ-ọmọ ọmọ rẹ marun ọdun, pẹlu Polly Sheppard, ọmọ ẹgbẹ ẹkọ Bibeli kan. Aya iyawo Pinckney ati awọn ọmọbirin meji tun wa ninu ile lakoko ti ibon. <ref>{{Cite web}}</ref> Awọn ti o pa ni a mọ bi: <ref>{{Cite web}}</ref> <ref>{{Cite web}}</ref> {{Div col}}
* [[Clementa C. Pinckney]] (41) – wòólì àti [[South Carolina Senate|alàgbà ilé-aṣòfin South Carolina]].
* Cynthia Marie Graham Hurd (54) – Bible study member and manager for the Charleston County Public Library system; sister of politician and former state senator [[Malcolm Graham (politician)|Malcolm Graham]].