Rodney Joseph Johnson: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Created by translating the page "Rodney Joseph Johnson"
k corr using AWB
Ìlà 1:
'''Rodney Joseph Johnson''' (October 24, 1965 - September 21, 2006)  jẹ́ agbófin ró lábé ilé iṣé ̣ọlọ́pàá  Houston . Ẹni tí ó lo ọdú mẹ́rìnlá (14 years) pẹ̀lú ilé iṣẹ́ nàà ṣáajú ìpapòdà rẹ̀ lẹ́nu iṣẹ́ ni ́ọjọ̣́ kọ̣kànlé-lógún oṣù kẹ̣́jọ, ọdún 2006.
 
Juan Leonardo Quintero tó jẹ́ ẹni tó gbònà àìtọ́ wọ ilẹ̀ <nowiki>[[Mexico]]</nowiki> lẹ́yìn tí wọ́n ti le kúrò ní ilẹ̀ <nowiki>[[America]]</nowiki> fún èsù ìfipá-báni lòpọ̀ tí ó hù sí ọmọbìnrin kan ṣùgbọ tí ó padà wọ ilú náà ó gbìyànjú láti dojú èsùn tí wọ́n fi kàn án "tí wọ́n sì fi sílẹ̀ lẹ́yìn tí ìwé ìròyìn gbe wì́pé ó ní àrùn ọpọlọ kan. "<ref name="Root">Jay Root, [https://www.texastribune.org/2016/02/11/quintero-case-was-poster-child-porous-border/ After Deportation, Killer Returned Easily to U.S.], ''Texas Tribune'' (February 11, 2016).</ref><ref>{{Cite web|title=Cop Killing Sparks Immigration Debate: Police Chief Blames Federal Government for Officer's Death|publisher=ABC News|accessdate=2010-04-03|url=http://abcnews.go.com/GMA/story?id=2487004}}</ref><ref>{{Cite web|title=Both Sides Find Fault With Effort to Deport Immigrants|work=The New York Times|author=James C. McKinley, Jr.|date=2009-07-25|accessdate=2010-04-03|url=https://www.nytimes.com/2009/07/26/us/26secure.html?pagewanted=all}}</ref> ní ọ̀dún 2008, Wọ́n dájọ́ ẹ̀wọ̀n gbére  life imprisonment fún Quintero fún ìwà ọ̀daràn rẹ̀ náà.<ref name="RogersLezon">Brian Rogers & Dale Lezon, [http://www.chron.com/news/houston-texas/article/Jurors-sentence-HPD-officer-s-killer-to-life-1536586.php Jurors sentence HPD officer's killer to life], ''Houston Chronicle'' (May 20, 2008).</ref>
Ìlà 12:
 
== Iṣẹ́ tí ́ ṣe kẹ́yìn kó tó kú  ==
Ni ojo kokanle-logbo osu kesan, odun 2006 (September 21, 2006,) Johnson  gan ni oko ti o n sare asapajude kan ni iwon 50 MPH si 30 MPH ni opopona Randolph nitosi Braniff, ti o un sumo William P. Hobby Airport southeast ti downtown. oko ti8 o sare asa-pajude yii je oko Olopon-Foodu (Ford pickup truck)  ni eyi ti o je pe Juan Leonardo Quintero lo waa. Johnson da oko naa duro, ti o si beere fun iwe-awako Quintero ni eyi ti . Quintero ko le mu jade fun idanimo. Jhonson ba kuku mu ti o si fi mamu-gaari si lowo, o tii sinu oko agbofinro re, o ti lekun mo. lati ko iwe ijabe-esun lolri Quintero. Nibi ti Jhonson ti n se eyi lowo ni Quintero ti ra pala yi owo re pada siwaju toun ti mamu-gaari owo re, ti o si mu ibon ilewo kan 9MM caliber handgun ti o so mo okun idi re ti o si yiin fun olopaa Johnson, amo ki Jhonson to ku, o gbiyanju lati te  ero ipe paja-wiri ti o wa nibi oko re, ni eyi ti o sofofo fun ile-ise olopaa wipe olopaa kan wa ninu idaanmu lowo lowo. leyin ti Quintero yinbon lu  Johnson tan,  o tun yinbon ti oko eso oju popo to wa nitosi ibe sugbon o tase. Nigba ti awon olopaa to ku debe, won ba Quintero leni ti o si jokoo seyin oko ti Jhons fi si tou ti mamu-gaari owo re pelu ibo t mu dani. Won si fi Quintero si ahamo rtin igba naa.
 
== Ìsìnkú àti ìṣẹ̀yẹ ẹni rere ==
Ìlà 25:
Juan Leonardo Quintero, ti o je omo marundinlogoji (35), ni o je arinrin-ajo lona ti ko bofin mu, ti o si tun ni akosile wipe o ni arun opolo atari isubu re latigba ewe re.<ref>{{Cite web|title=Immigrant Found Guilty Of Killing Officer|publisher=KPRC Houston|accessdate=2010-04-03|author=Mary Benton|date=2008-05-08|url=http://www.click2houston.com/news/16204502/detail.html|deadurl=yes|archiveurl=https://web.archive.org/web/20080613145818/http://www.click2houston.com/news/16204502/detail.html|archivedate=June 13, 2008}}</ref> Quintero koko wo U.S. ni odun 1994, lona aibofinmu nipa da Matamoros koja ti o si Houston.  Won tun mu ni 1995  fun iwa omuti para, bakan naa ni won tun m fun wiwa oko pelu iwe idanimo ti won fura si ni 1996. NI odun 1998, o bebe fun idariji lori iwa aito to hu si omode-binrin omo odun mejia (12)kan pelu ki won ba poun fowo eo ejo naa seyin. Ni  April 1999, won tii mole fun  rirufin irina, ti won si da pada si Mexico ni osu to te le. Ni opin odun 1999,  eni ti o ni okowo landscaping business ti o gba Quintero sise ni  Houston ya ni owo pe ki o fi ya oko ka ti won n pe ni coyote  pe ki o fi ko fi se fayawo koja ni ibode .
 
Leyinn ti  Quintero yinbo gbemi Johnson, kia ni won  ti mu ti wo si fi si ahamo awo olopaa .  O bebe pe oun ko moomo paa lati wipe ori ou ko pe rara . Adajo ti o gbo ejo naa ko teti gbo oro enu re, o si dajo ewon gbere fun ni odun 2008. Ewe, o btun je  okan lara awon ti owo te lasiko ti won  gbiyanju lati sa jade ni ogba ewon  Allan B. Polunsky Unit, ogba ewon ti o wa ni Livingston, Texas, ni odun 2010.<ref>{{Cite web|title=Cop killer in alleged prison escape try|agency=United Press International|accessdate=2010-04-03|url=http://www.upi.com/Top_News/US/2010/01/30/Cop-killer-in-alleged-prison-escape-try/UPI-27771264880681/}}</ref>
 
=== Ṣíṣe ìdájọ́ agbódegbà ọ̀daràn náà ===
Ni odun  2009, Robert Lane Camp, eni ti o ni ilese landscaping ti  o gba Quintero sise, ti o si ya nile gbe jewo pe looto ni oun jebi esun ti ijoba fi kan oun pe oun  gba alejo aito to wolu lona aito sile ti ou si raan lowlo lati huwa odaran sugbon ki ioba dakun-dabo ki won fowo wonu dariji oun ni ile-ejo  U.S. District Court for the Southern District of Texas . Ni  odun 2010 ni won da Camp lejo ewon osu meta pere  ninu ie ara re( home confinement),  ti won si tun fi si abe iso awo lopaa fu odidi oduo marun. Eleyii yoo je gege bi ijiya ati ikilo fun enikeni ti o ba tun gba alejo to wolu lona aito gege bi oun ti <ref>{{Cite press release|title=Business Owner Convicted of Harboring an Illegal Alien Sentenced|publisher=United States Attorney's Office for Southern District of Texas|url=https://www.justice.gov/archive/usao/txs/1News/Releases/2010%20May/051010%20Camp.htm|date=May 10, 2010}}</ref> U.S. Attorney Don DeGabrielle so ni Houston .<ref>{{Cite web|title=Employer of suspect in officer's death arrested: Prosecutors say illegal immigrant charged in killing of officer got help to re-enter U.S.|work=Houston Chronicle|accessdate=2010-04-03|url=http://www.chron.com/disp/story.mpl/front/5442207.html}}</ref>
 
== Àwọn ìtọ́ka sí ==