Ìgbéyàwó: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Ìlà 24:
 
'''Ìgbéyàwó Gangan:''' Èyí ni ayẹyẹ tó kẹ́yìn láṣà ìgbéyàwó nílẹ̀ Yorùbá láyé àtijó. Ó máa ń wáyé lẹ́yìn tí àwọn ọkọ-ojúọnà bá ti san gbogbo ẹrù ìdána. Àwọn ìdílé ìyàwó-ojú ọnà yóò wa sètò láti sìn ìyàwó lọ ilé ọkọ rẹ. Ọ̀kan-ọ̀-jọ̀kan àwọn ẹbí ìyàwó àti ọkọ á máa wúre fún ìyàwó àti ọkọ rẹ̀ lọ́jọ́ ìgbéyàwó. Jíjẹ àti mímu máa ń pọ̀ lọ́pọ̀ yanturu.
 
<ref name="Stella Dimoko Korkus.com">{{cite web | title=Asa Igbeyawo Ati Oju Ise Alarina Laye Atijo | website=Stella Dimoko Korkus.com | url=https://www.stelladimokokorkus.com/2018/08/asa-igbeyawo-ati-oju-ise-alarina-laye.html | language=ca | access-date=2019-11-14}}</ref>
://edeyorubarewa.com/a%e1%b9%a3a-igbeyawo/