Pete Edochie: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ìlà 1:
Oloye Pete Edochie, MON (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1947) jẹ́ àgbà-ọ̀jẹ̀, gbajúmọ̀ àti ìlúmọ̀ọ́kà òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ ẹ̀yà Ìgbò láti ìpínlẹ̀ Anambra, lorílẹ̀-èdè Nàìjíríà.<ref name="Nigeria 1947">{{cite web | title=Pete Edochie, Actor, Producer, Nigeria Personality Profiles | website=Nigeria | date=1947-03-07 | url=https://www.nigeriagalleria.com/Nigeria/Personality-Profiles/Actors-Actresses/Pete-Edochie.html | access-date=2019-11-29}}</ref> Sinimá àgbéléwò lédè Gẹ̀ẹ́sì àti Ìgbò ló ti ń kópa. Wọ́n kà á sí àgbà òṣèré sinimá-àgbéléwò tó lẹ́bùn eré sinimá ṣíṣe jùlọ nílẹ̀ adúláwọ̀ Áfíríkà.<ref name="The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News 2019">{{cite web | title=All You Need To Know About Veteran Actor Pete Edochie | website=The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News | date=2019-03-07 | url=https://guardian.ng/life/spotlight/all-you-need-to-know-about-veteran-actor-pete-edochie/ | access-date=2019-11-29}}</ref> Èyí hànde látàrí onírúurú àmìn ẹ̀yẹ tí ó ti gbà gẹ́gẹ́ bí òṣèré sinimá àgbéléwò, pàápàá jùlọ àmìn ẹ̀yẹ láti ọwọ́ African Magic àti Africa Film Academy. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé akọ̀ṣẹ́mọṣẹ́ olùṣàkóso àti gbajúgbajà agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni, ó di ìlúmọ̀ọ́kà òṣèré lọ́dún 1980 nígbà tí ó kópa gẹ́gẹ́ bí olú-ẹ̀dá ìtàn tí wọ́n pè ní Okonkwo nínú ìwé ìtàn àròsọ kan, Things Fall Apart tí àgbà-ọ̀jẹ̀ òǹkọ̀wé, Chinua Achebe kọ, tí wọ́n sọ di eré àgbéléwò orí ẹ̀rọ tẹlifíṣọ̀n NTA tó gbajúmọ̀ jùlọ nígbà náà. Gbajúmọ̀ Edochie pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ tí Ààrẹ àná, Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ fi dá a lọlá pẹ̀lú àmìn ẹ̀yẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Member of the Order of the Niger, MON lọ́dún 2003. Pete Edochie jẹ́ ọmọ ìjọ àgùdà.<ref name="Vkenya 2019">{{cite web | last=Vkenya | first=Dr. | title=Pete Edochie Biography: Wife, Sons, Daughter, Family, Proverbs & Quotes | website=Vkenya | date=2019-07-13 | url=http://vkenya.com/pete-edochie-biography-wife-sons-daughter-family-proverbs/ | access-date=2019-11-29}}</ref> <ref name="Austine Media 2019">{{cite web | title=10 Real Facts About Pete Edochie You Probably Didn't Know - Austine Media | website=Austine Media | date=2019-10-08 | url=https://austinemedia.com/10-real-facts-about-pete-edochie-you-probably-didnt-know/ | access-date=2019-11-29}}</ref>
 
==Ìgbà èwe rẹ̀==
 
Gẹ́gẹ́ bí a ṣe sọ ṣáájú, wọ́n bí Pete Edochie ní Ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1947. Ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Anambra ni ṣùgbọ́n Zaria, ní ìpínlẹ̀ Kaduna ló ti ṣe kékeré rẹ̀ dàgbà. Ó bẹ̀rẹ̀ ilé ìwé ní St. Patrick and James Primary School, Zaria, kí ó tó tẹ̀ síwájú ní St. John's College fún Ẹ̀kọ́ gírámà rẹ̀, lẹ́yìn èyí ló sí orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì fún ìtẹ̀síwájú ẹ̀kọ́ rẹ̀ tí ó sìn kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ìwé-ìròyìn àti ìgbóhùnsáfẹ̀fẹ̀. Lẹ́yìn èyí, ó ṣíṣe ní ilé iṣẹ́ ìjọba tó ń rí sí ọkọ̀ ojú-irin kí ó tó dára pọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ Nigeria Television Authority, NTA lọ́dún 1967 nígbà tó wà lọ́mọ ogún ọdún. Kò pẹ́ nídìí iṣẹ́ púpọ̀ kí ó tó dara pọ̀ mọ́ iṣẹ́ tíátà.<ref name="INSIDENOLLY 1947">{{cite web | title=Pete Edochie (Ebubedike) (Actor) - Filmography | website=INSIDENOLLY | date=1947-03-07 | url=https://www.insidenolly.ng/pete-edochie-ebubedike/ | access-date=2019-11-29}}</ref>
 
 
He got into radio broadcasting in 1967 at the age of 20[8] as a junior programmes assistant after which he was elevated to the level of a Director. He was director of programmes, but doubling sometimes as Deputy Managing Director and occasionally acting as Managing Director. He quit ABS because the government decided to politicise the affairs of their FM station, thereby resulting in the entire management being asked to move out, including him. He was to be the immediate successor to the MD but had to leave and enrol into the movie industry. Prior to that, he had featured in Things Fall Apart and had won an International Award. The BBC flew into Nigeria to interview him for his role in Things Fall Apart.[1]
 
In September 2017, Edochie endorsed Wikimedia movement in Nigeria by appearing in a video to increase awareness and use of Wikipedia among the older generations
 
==Àtòjọ àwọn sinimá àgbéléwò tó ti kópa==