Ayé: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Àmì ohùn
No edit summary
Ìlà 57:
'''Ilẹ̀-ayé''' (earth) tabi '''aye''' tabi ''[[ílẹ́ ọ̀gẹ́rẹ́]]'' tàbí''[[ilé-ayé]]'' je [[plánẹ́tì]] keta bẹ́rẹ́ láti [[Sun|òòrùn]], ósì jé èyí tí ó tóbi jùlo nínú àwọn plánẹ̀tì tì wọ́n ní ilẹ́ tí ó seè tè.
 
Ilé-ayé jé plánẹ́tì àkọ́kọ́ tí ó ní omi tó ń sàn ní odeojú rè. bẹ́ẹ̀ sinisìni ileIlé-ayeayé nikannìkan ni planetiplánétì ti a momọ̀ ni [[agbalaàgbálá-aye]] (universe) ti o ni ohun elemi. Aye ni [[papa gberingberin]] to je pe lapapo mo [[oju-oorun]] (atmosphere) to je kiki nitrogen ati oxygen n da abo bo ile-aye lowo [[atangbona]] (radiation) to lewu si emi. Bakanna oju-oorun ko gba awon [[yanrin-oorun]] laaye lati jabo si ile-aye nipa sisun won nina ki won o to le jabo s'ile-aye.
 
 
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ayé"