Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Gíríìsì"

21 bytes added ,  19:48, 11 Oṣù Kàrún 2020
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k (Demmy ṣeyípòdà ojúewé GríìsìGíríìsì)
{{Infobox Country
|native_name = Ελληνική Δημοκρατία<br />''Ellīnikī́ Dīmokratía''
|conventional_long_name = Hẹ́llẹ́nìkìOrílẹ̀-èdè Olómìnira Hẹ́llẹ́nẹ̀<br /> Hellenic Republic
|common_name = GríìsìGíríìsì
|image_flag = Flag of Greece.svg
|image_coat = Coat of arms of Greece.svg
|footnote3 = The [[.eu]] domain is also used, as in other [[European Union]] member states.
}}
'''GríìsìGíríìsì''' ({{IPA-en|ˈɡriːs|lang|en-us-Greece.ogg}}; {{lang-el|Ελλάδα}}, ''Elláda'', {{IPA-el|eˈlaða|IPA|Ellada.ogg}}; {{lang-grc|Ἑλλάς}}, ''Hellás'', {{IPA-el|helːás|IPA}}), bakanna gege bi '''Hellas''' ati fun ibise bi '''Helleniki Olominira''' (Ελληνική Δημοκρατία, ''Ellīnikī́ Dīmokratía'', {{IPA-el|eliniˈci ðimokraˈtia|IPA}}),<ref>{{cite web |url=https://www.cia.gov/library/publications/the-world-factbook/geos/gr.html |publisher=www.cia.gov |work=[[CIA]] |date=2007-03-15 |accessdate=2007-04-07 |title=World Factbook - Greece: Government}}</ref> je [[country|orile-ede]] kan ni guusuapailaorun [[Europe]], o budo si apaguusu opin [[Balkans|Balkan Peninsula]].
Griisi ni ile bode mo [[Albania]], [[Republic of Macedonia|Olominira ile Makedonia]] ati [[Bulgaria]] si ariwa, ati [[Turkey|Turki]] si ilaorun. [[Aegean Sea|Okun Aegeani]] dubule si ilaorun re, the [[Ionian Sea|Okun Ioniani]] si iwoorun, ati [[Mediterranean Sea|Okun Mediterraneani]] si guusu. Griisi ni o ni etiodo kewa togunjulo ni agbaye toje {{convert|14880|km|2|abbr=on|lk=out}} ni gigun, ti o ni opolopo iye awon [[List of islands of Greece|erekusu]] (bi 1400, 227 ni ibi ti aon eniyan ngbe), ninu won ni [[Crete]], [[Dodecanese]], [[Cyclades]], ati awon [[Ionian Islands|Erekusu Ioniani]]. Bi ogorin ninu ogorun ile Griisi ni o je ti awon oke, ninu ibi ti [[Mount Olympus|Oke Olympus]] ni o gajulo to je {{convert|2917|m|2|abbr=on|lk=out}}.