Ilẹ̀ Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
Content deleted Content added
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
No edit summary
Ìlà 1:
{{Infobox settlement
[[ILẸ̀ YORÙBÁ]]
| name = Ilẹ̀ Yorùbá
| official_name =
| native_name = {{small|Ilẹ̀ Yorùbá}}
| other_name = {{small|Southwest Nigeria, Western Nigeria, South and Central Benin, Central Togo}} and Ghana
| nickname = Ilẹ̀ Káarò-Õjíire
| settlement_type = Cultural region
| motto =
| anthem =
| image_skyline =
| imagesize =
| image_caption =
| image_flag =
| flag_size =
| image_seal =
| seal_size =
| image_shield =
| shield_size = 290px
| image_map = [[File:Yorubaland Cultural Area of West Africa.jpg|Yorubaland Cultural Area of West Africa|400px]]
| mapsize = 220px
| map_caption = {{map caption |location_color=green |country=<nowiki />Yorubaland |region=[[West Africa]]}}
| image_map1 =
| mapsize1 =
| map_caption1 =
| subdivision_type = Part of
| subdivision_name = {{BEN}}
{{NGR}}
{{TOG}}
| established_title = - Settlement of [[Ife|Ifẹ̀]]
| founder = '''PYIG''' (Proto [[Yoruba people|Yoruba]]-[[Itsekiri people|Itsekiri]]-[[Igala people|Igala]])
| established_date = 400 BCE
| established_title1 = - Oyo Empire
| established_date1 = 1400
| established_title2 = - British Colony
| established_date2 = 1862
| established_date3 = 1872
| established_title3 = - French Colony
| established_title4 = - Dahomey (Now Benin)
| established_date4 = 1904
| established_title5 = - Nigeria
| established_date5 = 1914
[[AKINỌLA ỌLÁNREWAJU]]
| seat_type = Regional capital
| seat = • [[Ife|'''Ilẹ̀-Ifẹ̀''']] (Cultural/Spiritual)
• '''[[Ibadan]]''' (Political)
• [[Lagos|'''Lagos/Eko''']] (Economic)
| seat1 = • '''[[Oyo-Ile]]''' (Old Political)
| parts_type = Composed of
| parts_style = coll
| parts =
| p1 = [[Oyo State]]
| p2 = [[Osun State]]
| p3 = [[Ogun State]]
| p4 = [[Ondo State]]
| p5 = [[Ekiti State]]
| p6 = [[Lagos State]]
| p7 = [[Kogi State]]
| p8 = [[Kwara State]]
| p10 = [[Ouémé Department|Ouémé]]
| p11 = [[Plateau Department|Plateau]]
| p12 = [[Collines Department|Collines]]
| p13 = [[Donga Department|Donga]]
| p14 = [[Borgou Department|Borgu]]
| p15 = [[Plateaux Region, Togo|Plateaux]]
| p16 = [[Centrale Region, Togo|Centrale]]
| government_footnotes =
| government_type = '''[[Monarchy|Monarchies]]'''
• '''[[Oba (ruler)|Oba]]''' ([[King]])
• '''[[Ogboni|Ògbóni]]''' ([[Legislature]])
• '''[[Oba (ruler)|Olóye]]''' ([[Tribal chief|Chiefs]])
• '''Balógun''' ([[Generalissimo]])
• '''Baálẹ̀''' (Village/Regional heads in Western Yorubaland)
• '''Ọlọja''' (Village/Regional heads in Eastern Yorubaland)
| area_magnitude =
| unit_pref = metric
| area_footnotes =
| area_total_km2 = 142,114
| area_land_km2 =
| area_water_km2 =
| area_total_sq_mi =
| area_land_sq_mi =
([[Idanre Hill|Idanre Inselberg Hills]])
| elevation_max_ft = 3461
| elevation_max_m = 1055
| elevation_min_ft = -0.7
| elevation_min_m = -0.2
| population_as_of = 2015 estimate
| population_footnotes =
| population_note = In Nigeria, Benin and Togo
| population_total = ~ 55 million
| population_density_sq_mi =
| demographics_type1 = Demographics
| demographics1_footnotes =
| demographics1_title1 = Language
| demographics1_info1 = [[Yoruba language|Yoruba]]
| demographics1_title2 = Religion
| demographics1_info2 = [[Christianity]], [[Islam]], [[Yoruba religion]]
| timezone = [[West Africa Time|WAT]] (Nigeria, Benin), [[GMT]] (Togo)
| utc_offset =
| coor_type =
| website =
| footnotes =
'''Ilẹ̀ Yorùbá''' ni [[cultural region|agbègbè ìgbéró àsà]] ilẹ̀ [[Yoruba people|àwọn ọmọ Yorùbá]] ní [[West Africa|Ìwọ̀òrùn Áfríkà]]. Ilẹ̀ Yorùbá fẹ̀ láti [[Nàìjíríà]], [[Benin]] títídé [[Togo]], agbègbè ilẹ̀ Yorùbá fẹ̀ tó 142,114 km2 106,016 km2 inú rẹ̀ (74.6%) bọ́sí Nàìjíríà, 18.9% bósí orílẹ̀-èdè Benin, àti 6.5% yìókù bósí orílẹ̀-èdè Togo. Ilẹ̀ ìgbéró àsà Yorùbá yìí ní iye àwọn ènìyàn bíi mílíọ́nù 55.
==Jẹ́ọ́gráfì==
==Ìtàn Àkọọ́lẹ̀ Yorùbá==
Gẹ́gẹ́ bí ìwádìí Àtàndá (1980), bí àwọn Yorùbá ṣe dé orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti àsìkò tí wọ́n tẹ̀dó síbẹ̀ kíi ṣe ìbéèrè tí ẹnikẹ́ni lè dáhùn ní pàtó nítorí pé àwọn baba nlá wọn kò fi àkọsílẹ̀ ìṣe àti ìtàn wọn sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àjogúnbá.
Line 9 ⟶ 118:
Àwọn ìtàn àtẹnudẹ́nu tí a gbọ́ nípa ìṣẹ̀dá yàtọ̀ sí ara wọn díẹ̀díẹ̀. Ìtàn kan sọ fún wa pé àwọn Yorùbá ti wà láti ìgbà ìwáṣẹ̀ àti láti ìgbà ìṣẹ̀dá ayé. Ìtàn ọ̀rùn pé kí ó wá ṣẹ̀dá ayé àti àwọn ènìyàn inú rẹ̀. Ìtàn náà sọ fún wa pé Odùduwà sọ̀kalẹ̀ sí Ilé-Ifẹ̀ láti ọ̀run pẹ̀lú àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀. Wọ́n sì ṣe iṣẹ́ tí Olódùmarè rán wọn ní àṣepé. Nípasẹ̀ ìtàn yìí, a lè sọ pé Ilé-Ifẹ̀ ní àwọn Yorùbá ti ṣẹ̀, àti pàápàá gbogbo ènìyàn àgbáyé.
Ìtàn mìíràn tí a tún gbọ́ sọ fún wa pé àwọn Yorùbá wá Ilé-Ifẹ̀ láti ilẹ̀ Mẹ́kà lábẹ́ àkóso [[Odùduwà]] nígbà tí ìjà kan bẹ́ sílẹ̀ ní ilẹ̀ Arébíà lẹ́yìn tí ẹ̀sìn Islam dé sáàrin àwọn ènìyàn agbègbè náà. Àwọn onímọ̀ kan nípa ìtàn ti yẹ ìtàn yìí wò fínnífínní, wọ́n sì gbà wí pé bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ṣe é ṣe kí àwọn Yorùbá ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn ará Mẹ́kà àti agbègbè Arébíà mìíràn kí wọ́n tó ṣí kúrò, ibi tí wọ́n ti ṣẹ̀ wá gan-an ni íjíbítì tàbí Núbíà. Àwọn onímọ̀ yìí náà gbà pé Odùduwà ni ó jẹ́ olórí fún àwọn ènìyàn yìí.
Kókó pàtàkì kan tí a rí dìmú ni pé Odùduwà ni olùdarí àwọn ènìyàn tí ó wá láti tẹ̀dó sí Ilé-Ìfẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìtàn méjéèjì tí a gbọ́ ṣe sọ. Tí a bá yẹ ìtàn méjéèjì wò, a ó rí i pé kò ṣe é ṣe kí Odùduwà méjèèjì jẹ́ ẹnìkan náà nítorí pé àsìkò tàbí ọdún tí ó wà láàrin ìṣẹ̀dá ayé àti àsìkò tí ẹ̀sìn Islam dé jìnna púpọ̀ sí ara wọn. Nítorí ìdí èyí a lè gbà pé nínú ìtàn kejì ni Odùduwà ti kópa. Ìdí mìíràn tí a fi lè fara mọ́ ìtàn kèjì ni pé lẹ́yìn àyẹ̀wò sí ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ Yorùbá fínnífínní, ó hàn gbangba pé Odùduwà bá àwọn ẹ̀dá Olọ́run kan ní Ilé-Ifẹ̀ nígbà tí ó dé ibẹ̀. Àwọn ìtàn kan dárúkọ Àgbọnmìrègún tí Odùduwà bá ní Ilé-Ifẹ̀. Èyí fihàn pé kìí ṣe òfìfò ní ó ba Ilé-Ifẹ̀, bí kò ṣe pé àwọn kan wà níbẹ̀ pẹ̀lú Àgbọnmìrègún. Èyí sì tọ́ka sí i pé a ti ṣẹ̀dá àwọ̣n ènìyàn kí ọ̀rọ̀ Odùduwà tó jẹ yọ, nítorí náà, kò lè jẹ́ Odùduwà yìí ni Olódùmarè rán wá láti ṣẹ̀dá ayé gẹ́gẹ́ bí a ti gbọ́ ọ nínú ìtàn ìṣẹ̀dá.
Line 21 ⟶ 130:
Lóde òní, Yorùbá wà káàkiri ilẹ̀ àwọn aláwọ̀ dúdú (Áfíríkà), Amẹ́ríkà àti káàkiri àwọn erékùsù tí ó yí òkun Àtìlántíìkì ká. Ní ilẹ̀ aláwọ̀ dúdú. A le ríwọn ní Nàìjíríà, Gáná, Orílẹ̀-Olómìnira Bẹ̀nẹ̀, Tógò, Sàró àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà àti àwọn erékùsù káàkiri, a lè rí wọn ní jàmáíkà, Kúbà, Trínídáádì àti Tòbégò pẹ̀lú Bùràsíìlì àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Yàtọ̀ sí ètò ìjọba olósèlú àwarawa tí ó fi gómìnà jẹ olórí ní ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan, a tún ní àwọn ọba aládé káàkiri àwọn ìlú nlánlá tí ó wà ní ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan. Díẹ̀ lára wọn ni Ọba ìbíní, [[Ọba Èkó]], [[Èwí tí Adó-Èkìtì]], [[Òbáró ti Òkéné]], [[Aláké]] tí Abẹ́òkúta, [[Dèji ti Àkúrẹ́]], [[Olúbàdàn]] ti Ìbàdàn, [[Àtá-Ója]] ti Òṣogbo, [[Sọ̀ún ti Ògbòmọ̀ṣọ́]] ati [[Aláàfin]] ti Ọ̀yọ́.
[[Baálẹ̀]] ní tirẹ̀ jẹ́ olórí ìlú kékeré tàbí abúlé. Ètò ni ó sọ wọ́n di olórí ìlú kéréje nítorí pé Yorùbá gbàgbọ́ pé ìlú kìí kéré kí wọ́n má nìí àgbà tàbí olórí. Aláàfin ni a kọ́kọ́ gbọ́ pé ó sọ àwọn olórí báyìí di olóyè tí a mọ̀ sí baálẹ̀.
Lábẹ́ àwọn olórí ìlú wọ̀nyí ni a tún ti rí àwọn olóyè orísìírísìí tí wọ́n ní isẹ́ tí wọ́n ń se láàrín ìlú, ẹgbẹ́, tàbí ìjọ (ẹ̀ṣìn). Lára irú àwọn oyè bẹ́ẹ̀ ni a ti rí oyè àjẹwọ̀, oyè ogun, oyè àfidánilọ́lá, oyè ẹgbẹ́, oyè ẹ̀ṣìn àti oyè ti agboolé bíi Baálé, Ìyáálé, Akéwejẹ̀, Olórí ọmọ-osú, Ìyá Èwe Améréyá, Mọ́gàjí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
==Èdè Yorùbá==
Ní báyìí, tí a bá wo èdè Yorùbá, àwọn onímọ̀ pín èdè náà sábẹ́ ẹ̀yà [[Kwa]] nínú ẹbí èdè [[Niger-Congo]]. Wọ́n tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ẹ̀yà Kwa yìí ló wọ́pọ̀ jùlọ ní sísọ, ní ìwọ̀ oòrùn aláwọ̀ dúdú fún ẹgbẹ̣ẹgbẹ̀rún ọdún. Àwọn onímọ̀ èdè kan tilẹ̀ ti fi ìdí ọ̀rọ̀ múlẹ̀ pé láti orírun kan náà ni àwọn èdè bí Yorùbá, Kru, Banle, Twi, Ga, Ewe, Fon, Edo, Nupe, Igbo, Idoma, Efik àti Ijaw ti bẹ̀rẹ̀ sí yapa gẹ́gẹ́ èdè ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tó dúró láti bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ọ̀dún sẹ́yìn.
Ọ̀kan pàtàkì lára àwọn èdè orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ni èdè Yorùbá. Àwọn ìpínlẹ̀ tí a ti lè rí àwọn tó n sọ èdè Yorùbá nílẹ̀ Nàìjíríà norílẹ̀ èdè Bìní. Tógò àti apá kan ní Gúúsù ilẹ̀ Amẹ́ríkà bí i Cuba, Brasil, Haiti, àti Trinidad. Ní gbogbo orílẹ̀-èdè tí a dárúkọ, yàtọ̀ sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, òwò ẹrú ni ó gbé àwọn ẹ̀yà Yorùbá dé ibẹ̀.
==Àṣà Yorùbá==
Ìràn Yorùbá jẹ́ ìran tó ti ní àṣà kí Òyìnbó tó mú àṣà tiwọn dé. Ètò ìsèlú àti ètò àwùjọ wọn mọ́yán lórí. Wọ́n ní ìgbàtbọ́ nínú Ọlọ́run àti òrìṣà, ètò ọrọ̀ ajé wọn múnádóko.
Line 41 ⟶ 150:
Yorùbá jẹ́ ìran tó kónimọ́ra. Gbogbo nǹkan wọn sì ló létò. Gbogbo ìgbésí ayé wọn ló wà létòlétò, èyí ló mú kí àwùjọ Yorùbá láyé ọjọ́un jẹ́ àwùjọ ìfọ̀kànbalẹ̀, àlàáfíà àti ìtẹ̀síwájú. Àwọn àṣà tó jẹ mọ́ ètò ìbágbépọ̀ láwùjọ Yorùbá ní ẹ̀kọ́-ilé, ètò-ìdílé, ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ tàbí irọ̀sírọ̀. Ẹ̀kọ́ abínimọ́, àwòse, erémọdé, ìsírò, ìkini, ìwà ọmọlúàbí, èèwọ̀, òwe Yorùbá, ìtàn àti àlọ́ jẹ́ ẹ̀kọ́-ilé. Nínú ètò mọ̀lẹ́bí lati rí Baálé, ìyáálé Ilé, Ọkùnrin Ilé, Obìnrin Ilé, Ọbàkan, Iyèkan, Ẹrúbílé àti Àràbátan.
Oríṣìíríṣìí [[oúnjẹ]] tó ń fún ni lókun, èyí tó ń seni lóore àti oúnjẹ amúnidàgbà ni ìràn Odùduwà ní ní ìkáwọ́. Díẹ̀ lára wọn ni [[iyán]], [[ọkà]], [[ẹ̀kọ]], [[mọ́ínmọ́ín]] àti [[gúgúrú]].
==ÌWÉ ÌTỌ́KASÍ==
*Adeoye, C.L. (1979): Àṣà àti Ìse Yorùbá, Oxford University Press.