Ìran Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 21:
|related-c= [[Ìran Ẹdó]], [[Tapa]], [[Igala]], [[Itsekiri]], [[Ìgbìrà]]
}}
'''Àwọn ọmọ Yorùbá ''' ti a pè ni ẹ̀nìyàn Yorùbá ni ibí yìí pọ̀ gan-an ni. I[[Ilẹ̀ Yorùbá]] ni púpò nínú wọ́n wa ni [[ìpínlẹ̀ Ẹdó]], [[Ìpínlẹ̀ Èkìtì]], [[Èkó]], [[Ìpínlẹ̀ Kwara]], [[ìpínlẹ̀ Kogí]], [[ìpínlẹ̀ Ògùn]], [[Ìpínlẹ̀ Òndó|Ìpínlẹ̀ Oǹdó]], [[ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun]], [[ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́|Ọ̀yọ́]]; àti wípé ọmọ Yorùbá wa ní orílẹ̀-èdè Olómìnira Benin ([[Benin|Dahomey]]), Sàró ([[Sierra Leone]]) àti [[Togo]], [[Brazil]], [[Cuba]], [[Haiti]], [[United States of America|Amẹ́ríkà]] ati Venezuela. Àwọn Yorùbá ni wọ́n se ipò keta ni pípò ni ilè [[Nàìjíríà]].
 
Àwọn Yorùbá jẹ́ àwọn ènìyàn kan ti èdè wón pín sí orísirísi. Àwọn Ìpín yíì ní a n ri; a máà lo ìpín èdè láti fi pé à èdè wa tí n se bi ti "Améríkà"; "Èkìtì"; "èkó"; "Ìjèbú"; "Ìjẹ̀ṣhà"; "Ìkálẹ̀"; "Ọ̀yó"; àti bebe lo. Láàrin èyí, la síì tún ní èdè ìfò tí nse àpẹẹrẹ èdè tó nípin si àwọn ìpín èdè tí o pọ̀.