Ìlú Ọ̀tà: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
kNo edit summary
Ìlà 1:
'''Ìlú Ọ̀tà'' (tì á tún mọ̀ sí '''Otta '''' ) jẹ́ ílú kán nì [[Ìpínlẹ̀ Ògùn|Ìpínlé Ogún]], ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]], àtí pé o ní iye àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹ́ olùgbéré-jáde tí ó tó 163,783 ń iye. Ọ̀tà ni ó
Ìlú tí [[Ìjọba ìbílẹ̀ Adó-Odò]] wà. [[Ọba]] alaye àti aláṣẹ tí ó wà lórí àga àṣẹ lọ́wọ́ lọ́wọ́ yí ni [[Ọ́lọ̀tá tí Ọ́tá]] [[Ọba Adéyẹmí AbdulKabir Ọba lánlẹ́gẹ́]] . Gẹ́gẹ́ bí ìtàn ti ṣe fi lélẹ̀, Ọ́ta jẹ́ olú ílù àwọ́ń [[Àwórì]] tí wọ́n jẹ́ ẹ̀yà kan nílẹ̀ [[Yorùbá]] <ref name="P.C. Lloyd 1962 225">{{Cite book|title=Yoruba Land Law|publisher=Oxford University Press|author=P.C. Lloyd|year=1962|page=225}}</ref>
 
Nínú akọsílẹ̀ ọ́dùń 1999, Ọ̀tà ni ó wà nípò kẹ́ta ní [[Ìpínlẹ̀ Ògùn]] tí ó ní ilé-iṣẹ́ tí ó pọ̀ jùlọ. <ref name="Ruhollah Ajibola Salako 1999 15">{{Cite book|title=Ota: The Biography of the Foremost Awori Town|publisher=Penink & Co|author=Ruhollah Ajibola Salako|year=1999|page=15}}</ref> [[Ọjà]] ńlá kan ati oju ọnà márosẹ̀ tí lọ láti [[Ìpínlẹ̀ Èkó]] lọ sí ìlú [[Abẹ́òkúta]], ìlú Ọ̀tà yí kan náà ni Ilé-iṣẹ́ ohun ọ̀gbìn Ààrẹ tẹ̀ ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]] nígbà kan ri, Ààrẹ [[Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ]] tí a mọ̀ sí [[Ọ̀tà Farm]]. Ba kan náà ni ilé-ìjọsìn ti [[church Winners 'Chapel]] tí ọ̀gbẹ́ni [[ David Oyèdépò]] jẹ́ olùdásílẹ̀ r.