Omi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
Ìlà 13:
=== Ìlera àti Ìbàyíkájẹ́ ===
[[Fáìlì:A man selling drinking water.jpg|thumb|227x227px|Ẹni tó ń ta omi tó ṣeé mu]]
"Omi tó ṣeé mu" là ń pè omi tí kò lárùn nínú ẹ̀. Bí omi kò bá ṣeé mu, aàá sẹ́ ẹ, tàbí kí a sè é a tó mu ún. Nǹkan bí àádọ́ta ọ̀kẹ́ lọ́nà 660 ènìyàn wà tí kò láǹfààní sí omi tó ṣeé mu.<ref name="McIntosh 2018">{{cite web | last=McIntosh | first=James | title=15 benefits of drinking water and other water facts | website=Medical and health information | date=2018-07-16 | url=https://www.medicalnewstoday.com/articles/290814 | access-date=2021-04-10}}</ref>
 
Omi tí a ò lè mu ṣùgbọ́n tí a lè lò ó láti wẹ̀ là ń pè é ní <nowiki>''omi tí kò léwu'' tàbí ''omi tó dára''</nowiki>. [[Klorínì|Kiloríìnì]] ni wọ́n máa ń fi sínú omi kí a lè lò ó láti wẹ̀ tàbí mu ún.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Omi"