Èdè: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 1:
 
 
Oríṣìíríṣìí àwọn Onímọ̀onímọ̀ ní ó ti gbìnyànjú láti fún èdè ní oríkì kan tàbí òmíràn, ṣùgbọ́n kí a tó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn oríkì wònyìí, èmi pàápàá yóò gbìnyìnjú láti sọ lérèfé ohun tí èdè túmọ̀ sí. ?
Èdè ní íníí ṣe pẹ̀lú ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ tí àwọn ènìyàn ń lò ní àwùjọ báyáyálà fún ìpolówó ọjà, ìbáraẹni sọ̀rọ̀ ojoojúmó, ètò ìdílé tàbí mọ̀lẹ́bí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Ní báyìí mo fẹ́ ṣe àgbéyẹ̀wò díẹ̀ lára àwọn onímọ̀ ti fún èdè. Gẹ́gẹ́ bí fatunsi (2001) ṣe sọ,
“Language Primarily as a System of Sounds exploited for the purpose of Communication bya group of humans.”
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Èdè"