Lateef Adedimeji: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Ìlà 29:
==Ìgbé-ayé àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀==
Gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú, wọ́n bí Lateef Adédiméjì ní Ọjọ́ kìíní oṣù kejì ọdún 1986 ni ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ṣùgbọ́n ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ògùn ni.<ref name="theinfopro.com.ng">{{cite web|url=https://theinfopro.com.ng/lateef-adedimeji-biography-net-worth-wikipedia/|title=Lateef Adedimeji Biography and Net Worth 2019}}</ref> O kàwé gboyè dìgírì nínú ìmọ̀ ìwé ìròyìn, ni ifáfitì [[Yunifásítì Olabisi Onabanjo]].<ref>{{cite web|url=https://www.pulse.ng/entertainment/movies/7-emerging-yoruba-movie-stars-you-need-to-know/vtfplhw|title=7 emerging Yoruba movie stars you need to know|work=Pulse.ng}}</ref>
 
 
==Ìgbé ayé tí ara ẹni==
Ni ọjọ kejidinlogun oṣù Kejìlá ọdún, 2021, Adedimeji fẹ afesona re , [[Oyebade Adebimpe]] ni ìgbéyàwó tí ọ l'arin rìn.<ref>{{Cite web|url=https://www.bbc.com/pidgin/media-59712969.amp|title=See photos from actor Lateef Adedimeji wedding wit colleague Adebimpe Oyebade|date=18 December 2021}}</ref>
 
==Àwọn Ìtọ́kasí==