ISO 639-1: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 1:
'''ISO 639-1:2002''', ''Àwọn àmìọ̀rọ̀ fún ìṣojú àwọn orúkọ àwọn èdè {{--}} Apá 1: àmìọ̀rọ̀ Alpha-2'' ni apa kinni [[ISO 639]] awon eseese [[International Organization for Standardization|opagun kariaye]] fun awon amioro ede. Apa kinni dalelori iforukosile awon amioro leta meji. Awon amioro leta meji 136 ni won je fiforukosile. Awon amioro ti won je fiforukosile je ti gbogbo awon ede agbaye koko.
 
Awon amioro wonyi je wuwulo kariaye lati se ikekuru ede. Fun apere:
These codes are a useful international, and formal, shorthand for indicating languages. For example:
*[[èdè Yorùbá|Yorùbá]] je sisoju pelu <tt>yo</tt>
*[[English language|Geesi]] je sisoju pelu <tt>en</tt>
Ìlà 7:
*[[German language|Èdè Germany]] je sisoju pelu <tt>de</tt> (lati [[endonym]] ''[[Deutsch]]'')
*[[Japanese language|Japanese]] je sisoju pelu <tt>ja</tt> (botilejepe [[endonym]] re ni ''[[Nihongo]]'')
*[[Swahili language|Èdè Swahili]] je sisoju pelu <tt>kw</tt> (lati [[endonym]] [[Kiswahili]])
*[[Portuguese language|Portuguese]] je sisoju pelu <tt>pt</tt>
*[[Spanish language|Spanish]] je sisoju pelu <tt>es</tt> (lati [[endonym]] ''[[Español]]'')
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/ISO_639-1"