Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ṣàngó"

133 bytes added ,  10:26, 13 Oṣù Kínní 2007
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
Sàngó
 
Yorùbá bò wọ́n ni àjànàkú kojá a morí nnkan fìrí, bí a bá rí erin, káwípe a rí erin ní òrò sàngó jé láàárin àwon òrìsà ile e Yorùbá. Sàngó jé òrìsà takuntakun kan gbògíìgbòógì laarinláàárín àwon òrìsà tókù ní ilè e Yorùbá. Ó jé orisà tí ìran rè kún fún ìbèrù. Ìrísí, ìṣe àti ìsọ̀rọ̀ rẹ̀ pàápàá kún fún ìbèrù nígbàtí ó wà laaye nítorípé ènìyàn la gbogbọ́ pe sàngó jejẹ́ télè kí ó tó di òrìsàòrìṣà ààráàrá. ItanÌtàn so wipewí pé omo Òrányàn ni sangósàngó i seṣe atiàti pe Oya, ÒsunÒṣun ati Obà jejẹ́ iyawoìyàwó rerẹ̀.
 
ÌhùwàsìÌhùwàsí búburú ati dídá wàhalá ati ìkolura pèlú ìjayée-ìjayé fàmílétè-kí-n-tutó pò lówó sàngó gégé bi Oba to beebẹ́ẹ̀ tititítí ó fi di òtéyímiká., Èyíèyí jásí wípéwí pé tomodétọmọdé tàgbà dìtè mó o. Wón fi ayé ni í lára. Ó sì fi ìlú Òyó sílè nígbèyìn-gbéyín. Ó pokùnso sí ìdí igi àyàn kan lébà ònà nítòsí Òyó nígbàtí Oya: ÌyàwoÌyàwó rerẹ̀ kan tókù náà sì di odò.
 
Ogbón tí àwon ènìyàn sàngó tókù dá láti fi bá àwon òtá rè jà nípa títítíti iná bolé won àti béèbéè lo ni ó so sàngó di òrìsàòrìṣàwonwọ́n ń bo títí dòní tí wón sì ńfi enu won tubatúúbá wípéwí pé sàngó sangó kòsoso: Oba koso.
 
ÀWON ORÚKO TÍ SÀNGÓ Ń JÉ
 
OrísirísíOríṣiríṣi orúko ni a mòmọ sàngó nínú èyí tí gbogbo won sì ní ìtumò tàbí ìdí kan pàtó ti a fi ńpè wọ́n béè. Àwon onikoorúko biibíi ìwònyìí.:
 
1. OlukosoOlúkòso: EnitíẸnití a mò momọ́ kòso tàbí oba tí ó wolè sí kòso.
 
2. ArèfúnjayéArèkújayé:
 
3. Àjàlájí:
4. Ayílègbe Òrun:
 
5. Olójú Orógbó: nítorípé orógbó ni obì tirè, òun ni ó sì máa ńsàfééríń ṣàféérí nígbà ayé rè. OrógbóOrógbó náà sì ni a maamáa nloń nilo ní ojúbo saàngósàngó tititítí di onìòní.
 
6. Èbìtì-àlàpà-peku-tiyètiyè: OrisaÒrìṣà tí ó máa ńfiń fi ìbínú gbígbóná pa ènìyàn ni àpalàyà tàbí àpafòn.
 
7. Onibon òrun: gégé bí òrìsà ó ń mú kí ààráàrá sán wá latiláti ojú òrun pèlú ìrókèkè tó lágbára.
 
8. Jàkúta: gégé bí orisaòrìṣànfiń fi òkúta jà (edunedùn ààráàrá). IrufeIrúfẹ́ òkúta kékeré kan tí ó máa sekúpa ènìyàn nípasènípasẹ̀ sàngó
 
9. Abotumo-bí-owú: Òrìsà o leeléè wolewolé pa eniyan bajeènìyàn bi eni pepé erù eruń nla ni oó woluwólu iruirú eni beebẹ́ẹ̀.
 
10. Èbìtì-káwó-pònyìn-soro: IrufeIrúfẹ́ OrisaÒrìṣà ti oó jejẹ́ wipe ìsowópé ìṣowó-sekupasekúpa asebiiasebi rerẹ̀ maamáa ńya ènìyàn lénu gidigidi.
 
11. Alágbára-inú-aféfé: Òrìsà tí ó jé wípé owojaowọ́jà a re, máa ńwá láti inú aféfé tàbí òfurufú ni.
 
12. Abánjà-majebimájẹ̀bi: òrìsàòrìṣà tíí jà láì sègbèṣègbè léhìnléyìn asebiaṣebi tàbí seṣe àsìmúàṣìmú elòmíràn fún oníséoníṣé ibi.
 
13. Lánníkú-oko-oya: Òrìsà tí o ni èrù iku níkàwóóníkàwó.
 
14. Òkokonkò èbìtì: Òrìsà tí ó le subú lu ènìyàn bii ìgànnán tí ó ti denukolèdenukọlè.
 
15. Eléèmò: Òrìsà tí ó ni èèmò.
8

edits