Èdè Àmháríkì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
New page: Amharic Amuhariiki Amariiki Èdè Sèmítíìkì (Semitic) kan ni eléyìí tí nnkan bú mílíònu márùndínlógún ń so gégé bí èdè àkókó...
 
interwiki
Ìlà 6:
 
Èdè Sèmítíìkì (Semitic) kan ni eléyìí tí nnkan bú mílíònu márùndínlógún ń so gégé bí èdè àkókó ní Ethopia (ìtópíà). Níbè, wón ń lò ó gégé bí tí ìjoba ń mú lò. Àwon bú mílíònù márùn-ún ni ó ń so èdè yìí ní agbègbè Ethiopia nígbà tí  àwon òpòlopò mílíònù mìíràn ń so èdè yìí gégé bí èdè kejì àkókúntenu ní Ethiopia àti Sudan (Sùdáànù). Láti nnkan bíi séńtúrì kerìnlá (14th Century) ni èdè yìí ti ní àkosílè. Àkotó Amharic ni wón fi ko ó sílè. Àkotó yìí ní Kóńsónántì métàlélógbòn òkòòkan won sì ní èdà méjeméje. Èdà kóńsónántì tí ènìyàn yóò mú lò dúró lóró fáwèlì tí kóńsónántì náà yóò bá je yo. Àbá ti ń wáyé nípa pé kí àtúnse wà fún àkotó yìí. Àwon kan sì ti kóra won jo fún ìpolongo láti so èdè yìí di àjùmòlò (Standardisc).
 
 
[[en:Amharic language]]
[[af:Amharies]]
[[am:አማርኛ]]
[[ar:لغة أمهرية]]
[[bg:Амхарски език]]
[[br:Amhareg]]
[[bs:Amharski jezik]]
[[ca:Amhàric]]
[[cs:Amharština]]
[[de:Amharische Sprache]]
[[es:Idioma amhárico]]
[[et:Amhari keel]]
[[fr:Amharique]]
[[hsb:Amharšćina]]
[[id:Bahasa Amharik]]
[[it:Lingua amarica]]
[[ja:アムハラ語]]
[[ka:ამჰარული ენა]]
[[ko:암하라어]]
[[nl:Amhaars]]
[[pl:Język amharski]]
[[pt:Língua amárica]]
[[ru:Амхарский язык]]
[[sk:Amharčina]]
[[sl:Amharščina]]
[[sv:Amhariska]]
[[zh:阿姆哈拉语]]