Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ṣàngó"

23 bytes removed ,  17:44, 8 Oṣù Kàrún 2007
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
Sàngó
 
Yorùbá bò wọ́n ni àjànàkú kojá a morí nnkan fìrí, bí a bá rí erin, káwípe a rí erin ní òrò sàngósàngó jé láàárin àwonàwon òrìsà ile eilee Yorùbá. SàngóSàngó jé òrìsà takuntakun kan gbòógì láàárín àwonàwon òrìsà tókù ní ilè eilèe Yorùbá. Ó jé orisàorisà tí ìran rè kún fún ìbèrù. Ìrísí, ìṣe àti ìsọ̀rọ̀ rẹ̀ pàápàá kún fún ìbèrù nígbàtí ó wà laaye nítorípé ènìyàn la gbọ́ pé sàngó jẹ́ télè kí ó tó di òrìṣà àrá. Ìtàn so wí pé omo Òrányàn ni sàngó i ṣe àti pé Oya, Òṣun ati Obà jẹ́ ìyàwó rẹ̀.
 
Ìhùwàsí búburú ati dídá wàhalá ati ìkolura pèlú ìjayé fàmílétè-kí-n-tutó pò lówó sàngó gégé bí Oba tó bẹ́ẹ̀ títí ó fi di òtéyímiká, èyí jásí wí pé tọmọdé tàgbà dìtè mó o. Wón fi ayé ni í lára. Ó sì fi ìlú Òyó sílè nígbèyìn-gbéyín. Ó pokùnso sí ìdí igi àyàn kan lébà ònà nítòsí Òyó nígbàtí Oya: Ìyàwó rẹ̀ kan tókù náà sì di odò.
Anonymous user