Joycelyn Elders

Olóṣèlú

Minnie Joycelyn Elders (abiso Minnie Lee Jones; August 13, 1933) je is an American oniwosan omode ati alakoso eto ilera igboro. O je ogagun igbakeji adari ni ile-ise awon omose alafunse ise ilera igboro ati omo Afrika Amerika akoko to je yiyan sipo gege bi Oniwosan Agba Orile-ede Amerika, o fi ipo yi sile ni 1994. Lowolowo Elders je ojogbon eniowo ninu eko iwosan omode ni Yunifasiti Arkansas fun Sayensi Oniwosan.

Joycelyn Elders
15th Surgeon General of the United States
In office
September 8, 1993 – December 31, 1994
ÀàrẹBill Clinton
AsíwájúRobert A. Whitney (acting)
Arọ́pòAudrey F. Manley (acting)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Minnie Lee Jones

Oṣù Kẹjọ 13, 1933 (1933-08-13) (ọmọ ọdún 90)
Schaal, Arkansas, U.S.
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic
Military service
Branch/servicePublic Health Service Commissioned Corps, United States Public Health Service
Years of serviceUSA: 1953–1956
RankUSPHS: Vice Admiral


Itokasi àtúnṣe