Ọdún
Ọdún kan jẹ́ iye àsìkó tí ó gba pílánẹ̀tì Ilẹ̀-ayé làti fi yípo Òòrùn kà lẹ́ẹ́kan péré. Ní fífàgùn, a leè fi èyí múlẹ̀ fún pílánẹ̀tì yó wù. Bí àpẹẹrẹ: "ọdún Máàsì" kan yí ò jẹ́ àsìkò tí yí ò gba Máàsì láti yípo Òòrùn léèkan.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |