Pál Schmitt
Pál Schmitt (ojoibi 13 May 1942 ni Budapest) je oloselu ara Hungari ati lowolowo Agbenuso Ile Asofin ile Hungari lati 14 May 2010. O je didiboyan bi Aare ile Hungari pelu ibo 263 si 59 ni Ile Asofin ile Hungari, o bo si ori aga ni 5 August 2010 de 2012.
Pál Schmitt | |
---|---|
Aare ile Hungari | |
In office 6 August 2010 – 2 April 2012 | |
Alákóso Àgbà | Viktor Orbán |
Asíwájú | László Sólyom |
Arọ́pò | László Kövér (Acting) |
Speaker of the National Assembly | |
In office 14 May 2010 – 5 August 2010 | |
Asíwájú | Béla Katona |
Arọ́pò | László Kövér |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Kàrún 1942 Budapest, Hungary |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Fidesz |
Profession | Fencer |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |