Pápá ìseré Mobolaji Johnson Arena jẹ́ pápá ìseré tí ówà fún òpòlopò eré idayara ní ìlú Èkó. O jé pápá ìseré ti òpòlopò àwon egbé agbábolù ni Èkó n lò fún gbigba boolu à fesè gbá, pàápa jùlo àwon egbé Ikorodu United F.C., Stationery Stores F.C., First Bank àti Julius Berger FC. Pápá ìṣeré náà le gba egbèrún mewa(10,000) ènìyàn ó sì jẹ́ pápá ìseré tí àkókó dá ní Nàìjíríà.[1] Pápá ìseré náà wà ní egbe Tafewa Belewa Square ní ìlú Èkó, a kó pápá ìseré náà ní 1930, odún mewa léyìn rè, a só ní orúko Oba George V. Laarin 1963 sí 1973, a bèrè sí ún pe ní pápá ìseré ilú Èkó. Wón tún padà tun kó tí wón sì tun se ní 1980s.[2]

Pápá ìṣeré Onikan

Àwon ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Onikan Stadium, Lagos Photos & Reviews". Hotels.ng Places. Retrieved September 10, 2022. 
  2. "See The New Look Of The Reconstruction And Upgrade of the Onikan Stadium – Photos". AutoReportNG. May 23, 2019. Retrieved September 10, 2022.