Pópù Fransisi 1k (Látìnì: Franciscus PP.,) abiso Jorge Mario Bergoglio ni o̩jó̩ ke̩tàdínlógún, osù kejìlá, o̩dún 1936) ni Popu lowolowo.

Francis
Pope Francis ni osù ke̩jo̩, o̩dún 2014
Papacy begano̩jó̩ ke̩tàlá osù ke̩ta, o̩dún 2013
PredecessorBenedict XVI
Ordinationo̩jó̩ ke̩tàlá osù kejìlá, o̩dún 1969 (by Ramón José Castellano)
Consecrationo̩jó̩ ke̩tàdínló̩gbò̩n osù ke̩fà, o̩dún 1992
Created Cardinalo̩jó̩ mókànlélógún osù kejì, o̩dún 2001
Personal details
Born17 Oṣù Kejìlá 1936 (1936-12-17) (ọmọ ọdún 87)
Buenos Aires, Argentina