Pak Hon-yong

(Àtúnjúwe láti Park Heon-young)

Park Heon-young(박헌영 朴憲永, 28 May 1900 - 5 December 1956) je oloselu, oniroyin ati asekomunisti ara Kòréà Gúúsù to kopa ninu gbigba ilominira ile Korea. Oruko alaje re ni Yijeong tabi Yichun.

Park Heon-young (1950)