Paschal Chigozie Obi
Paschal Chigozie Obi je olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà . O ṣiṣẹ gẹgẹbi ọmọ ẹgbẹ ti o nsoju Ideato North ati Ideato South ni Ile ìgbìmò Aṣoju sofin . [1] [2]
Paschal Chigozie Obi | |
---|---|
Member of the House of Representatives of Nigeria (2019-2023) from Imo | |
Constituency | Ideato North/Ideato South |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 15 July 1970 Obiohia, Ideato South |
Aráàlú | Nigeria |
Occupation | Politician |
Profession | Doctor |
Esin
àtúnṣePaschal Chigozie Obi jẹ Kristiani oni igbagbọ.